Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Performer
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Vocals
Babatope Joseph Temidayo
Babatope Joseph Temidayo
Drums
COMPOSITION & LYRICS
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Songwriter
Babatope Joseph Temidayo
Babatope Joseph Temidayo
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Executive Producer
Babatope Joseph Temidayo
Babatope Joseph Temidayo
Producer
Prince Oladeji Sunday Adele
Prince Oladeji Sunday Adele
Mixing Engineer
Iredumare Opeyemi
Iredumare Opeyemi
Executive Producer

Lyrics

Ladies
Ah ah ah Ẹ̀yin ọ̀tá mi ẹ rọra sáré o
Ẹ̀yin ọ̀tá mi ẹ rọra sáré o
Ọ ọ̀ gbọ́ bí mo ṣe ń wí
Arábámbí mi ọkùnrin ogun
Ẹ̀yin ọ̀tá mi ẹ rọra sáré o
Orí là á ní ká tó tọrọ ohun gbogbo
Àrìnká mà ń já bàtà, ẹ ẹ̀ rọra
Inú ni bíni kò kan t’àìmọwáhù
Gbogbo bínú bínú ẹ má ṣe bínú iṣẹ́ Ọlọ́hun Ọba
Orí là á ni ká tó tọrọ ohun gbogbo
Ẹ̀yin ọ̀tá mi ẹ rọra sáré o
(Ìgbà mi ń yí ọwọ́ agogo kò dúró lójú kan)
(Ìgbà mi ń yí ọwọ́ agogo kò dúró lójú kan)
(Ìgbà kan ń lọ ìgbà kan ń bọ̀ ah ah)
(Ìgbà kan ń lọ ìgbà kan ń bọ̀ ah ah)
(Ah ah ah ah ah ah ah ah ah)
(Oh oh oh oh oh oh oh oh oh)
(Eh eh eh eh eh eh eh eh eh)
(Awn aan awn awn awn awn awn awn awn)
Kádàrá gbogbo wa ṣe ọ̀tọ̀tọ̀
Ẹ ẹ̀ rọra
Alábọ̀sí a máa lówó
Alábósì a máa bímọ
Alábósì a máa lówó o
Alábòsí a máa bímọ
Àtúbọ̀tán alábọ̀sí kìí ya dáadáa
Ẹ̀dá ló ń sáré ṣèbí final decision ń bẹ lọ́wọ́ Ọlọ́hun Ọba
Ohun tó jọra la fi ń wé’ra
Ohun tó jọra la fi ń wé’ra wọn
Afẹ́fẹ́ ti fẹ́ a ti rí fùrọ̀ adìẹ
A rí ti tòlótòló o
N ọ̀ gbọ́ ẹ̀yin ọ̀tá mi ẹ rọra sáré o
(Ìgbà mi ń yí ọwọ́ agogo kò dúró lójú kan)
(Ìgbà mi ń yí ọwọ́ agogo kò dúró lójú kan)
(Ìgbà kan ń lọ ìgbà kan ń bọ̀ ah ah)
(Ìgbà kan ń lọ ìgbà kan ń bọ̀ ah ah)
(Ah ah ah ah ah ah ah ah ah)
(Oh oh oh oh oh oh oh oh oh)
(Eh eh eh eh eh eh eh eh eh)
(Awn aan awn awn awn awn awn awn awn)
Listening to fools iscas important as listening to genius
From geniuses you learn what to do
And from fools you learn what not to do
The truth always seems crazy in a world full of lies
Ahn Ahn
Be sure you put your fit in the right place
There is time fam
If your dream don't scare you then they aren't big enough
(Arábámbí Olúkòso Ṣàngó ọkọ ọya)
(Iná lójú iná lẹ́nu àkàtà yẹrìyẹrì)
(Ṣàngó o Olúkòso arẹ̀kújayé)
Grace without letter G is race
Check yourself before you wreck yourself
It is the only path which leads to growth
Ah ah ah ah ah ah ah ah ah)
(Oh oh oh oh oh oh oh oh oh)
(Eh eh eh eh eh eh eh eh eh)
(Awn aan awn awn awn awn awn awn awn)
(Ìgbà mi ń yí ọwọ́ agogo kò dúró lójú kan)
(Ìgbà mi ń yí ọwọ́ agogo kò dúró lójú kan)
(Ìgbà kan ń lọ ìgbà kan ń bọ̀ ah ah)
(Ìgbà kan ń lọ ìgbà kan ń bọ̀ ah ah)
Written by: Babatope Joseph Temidayo, Olasunkanmi Ayinde Marshal
instagramSharePathic_arrow_out