Lyrics

The time is now, new fuji vibes
Ọmọ naija, ẹ mà ṣeré keré
Erékeré ni n doyún k'oyún
Oyún k'oyún ni n dí ọmọ k'ọmọ
Ọmọ k'ọmọ ni n n'ilé lara
Ọmọ naija, ẹ mà ṣeré keré
Erékeré ni n doyún k'oyún
Oyún k'oyún ni n dí ọmọ k'ọmọ
Ọmọ k'ọmọ ni n n'ilé lara
Èmi ati ẹ
Ìwọ ati èmi
Lo le tún Nigeria ṣe
Ẹjẹ a múrà si
Èmi ati ẹ
Ìwọ ati èmi
Lo le tún Nigeria ṣe
Ẹjẹ a múrà si
Mi o rí ìbì to dábì ìlú mi o
(Naija)
Mé lé gbàgbé ìlú mi o
(Naija)
Àjò o dún ko dàbí ilé o
(Naija)
Ilé pá mi yè mi o
(Naija)
Ẹ pẹlẹ n'bẹ̀yẹn
Ẹ pẹlẹ n'bẹ̀yẹn, ijó re
Ẹ pẹlẹ n'bẹ̀yẹn
Ẹ pẹlẹ n'bẹ̀yẹn, ijó re
Èmi Ayinde Omogbolahan
Mo dé bi mo ṣe n dé
Mo ni kike oloburo
O jọ ti ẹiyẹ k'ẹiyẹ nínú okó
Ke mà wú lẹ ṣe apa mo inú
Gbángbá di ẹkùn, omo Anifowose o
Baba Wasi, Olaronke
Ko si bi to da bi ìlú mi o
(Naija)
Mé lé gbàgbé ìlú mi o
(Naija)
Àjò o dún ko dàbí ilé o
(Naija)
Ilé pá mi yè mi o
(Naija)
Ìbì k'ìbì tó wa around the world
Ẹ jẹ ká fall in line
Teni n'teni, te ki sa n ta tan
You better fall in line
Joshua, Heavy weight boxing champion
O má ti carry go
Àjò o dún ko dàbí ilé o
(Naija)
Ilé pá mi yè mi o
(Naija)
Arabambi, Ìré tó tọrọ ti dé o
Wasiu Ayinde, Ìré tó tọrọ ti dé o
Ayinde ade mi Wasiu
Ayé n binú kadara wọn ti gbàgbé àkúnlẹ yàn
Èni èlẹni ko ni gbá ìṣe rẹ ṣe
Àni ko ba mi ṣe amin ẹ
O dẹ jọ̀
O dẹ jọ̀
O dẹ jọ̀
O dẹ jọ̀
Perry Aroma sodun o
O ti nà àwọ ya
O n'àwọ dè
O ti nà àwọ ya
Perry Aroma sodun o
O ti nà àwọ ya
O n'àwọ dè
O ti nà àwọ ya
Ọmọ naija, b'àbá ni sùúrù
Ohun tó lọ à bọ
Ọmọ naija, b'àbá ni sùúrù
Ohun tó lọ à bọ
Ohun ti o tò, mo l'omà ṣekú
Gbogbo wa à f'ojú rí
Èyí ti o tò, mo l'omà ṣekú
Gbogbo wa à f'ojú rí
Èyí ti o tò, mo l'omà ṣekú
Gbogbo wa à f'ojú rí
Àni ti o tò, mo l'omà ṣekú
Gbogbo wa à f'ojú rí
Uh, yeah, eh
Take your time, begin dey dance o
Take your band, begin dey whine
Money don enter account
Take your time, begin dey smile o
Bo pè boya, akalolo a pé baba
Uh, oh
Make you start begin dey move o
Forget your sorrow, yeah, yeah, yeah
Everything go come, omo na turn by turn
Everything go dey, omo na turn by turn
I just want you to know
Everything go better
I just want you to know
Everything go dey better
Uh, oh, oh, oh, oh, yeah
Mi o rí ìbì to dábì ìlú mi o
(Naija)
Mé lé gbàgbé ìlú mi o
(Naija)
Àjò o dún ko dàbí ilé o
(Naija)
Ilé pá mi yè mi o
(Naija)
(It's maestro on the beat, baby)
Written by: Teni, Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
instagramSharePathic_arrow_out