Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Composer

Lyrics

[Verse 1]
Ẹṣin to ṣiwaju n lo gba fe
Ẹṣin to ṣiwaju n lo gba fe o
Ẹyin tẹ n ṣètò ẹ gbefe fun
Igbá funfun loromi, igbá funfun loromi o
Ẹni ba mọwẹ ko ka lọ
Ẹṣin to ṣiwaju n lo gba fe
Ẹṣin to ṣiwaju n lo gba fe o
Ẹyin tẹ n ṣètò kẹ gbefe fun
[Verse 2]
Igbá funfun loromi, igbá funfun loromi o
Ẹni ba mọwẹ ko ka lọ
Ori ọmọ lo ṣọmọ, ìyá ati bàbá ọmọ lo kọmọ yọ o, ọta o gbero wí pé ko da
Igbá funfun loromi,igbá funfun loriomi o
Ẹni ba mọwẹ ko ka lọ
Ori ọmọ lo ṣọmọ, ìyá ati bàbá ọmọ lo kọmọ yọ o, ọta o gbero wí pé ko da
Igbá funfun loriomi, igbá funfun loromi o
Ẹni ba mọwẹ ko ka lọ
[Verse 3]
Asalamu alekun o, gbogbo Eko federal o
Asalamu alekun o, gbogbo Eko federal o
Ológbowó ṣe ti ẹ, o perengede
Ìsàlẹ Ọfin ṣe ti ẹ, o perengede
Ìsàlẹ Eko ṣe ti ẹ, o perengede
Ẹpẹtẹdo ṣe ti ẹ, o perengede
Lafiaji ṣe ti ẹ, o perengede
Campus o ṣe ti ẹ, o perengede
[Chorus]
Igi gbogbo, igi gbogbo ni sowó o, ọtọ ni tobì
Ológbowó ọtọ, Oke Popo ọtọ
Ẹ r'Oko Faji kẹ d'Ọnala o
Kaabọ o, kaabọ
Kaabọ o, kaabọ
Oko Faji tajo de o, kaabọ o
Mo kení, mo kejì, mo kẹta ọrọ gbenu ọlọrọ ma le sọ
Kaabọ o, kaabọ
Kaabọ o, kaabọ
Oko Faji ta jo de o, kaabọ o
[Verse 4]
Ọmọ Eko federal mi o
Lọkunrin lobinrin gbogbo wa
A ṣọdun ọdun yii a o ṣẹẹmi si tọmotọmo
Igunnugun ki pọdún jẹ o
A la rọdun ọdún yii lowo, lọmọ lalaafia ara
Gbogbo wa la o ṣe pupọ ọdun laye o, Ayinde o
[Chorus]
Igi gbogbo, igi gbogbo ni sowó o, ọtọ ni tobì
Ológbowó ọtọ, Oke Popo ọtọ
Ẹ r'Oko Faji kẹ d'Ọnala o
Kaabọ o, kaabọ
Kaabọ o, kaabọ
Oko Faji tajo de o, kaabọ o
Written by: Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
instagramSharePathic_arrow_out