Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Producer
Segun Michael Ajayi
Segun Michael Ajayi
Producer

Lyrics

K1 de ultimate
Fújì, the sound
Ọlọ́run ló fi rán èmi Àyìndé o
God sent
Ìyá àti bàba wọn bí mi da
Èmi gangan mo tún tún ara bí
Lorúkọ òhun sẹ ń dá si
Ìyá àti bàbá wọn bí mi da
Èmi gangan mo tún tún ara bí
Lorúkọ òhun sẹ ń dá si
Ọmọ gidi ṣá lò yé ka yà
Ká sì tuń jé àrí kọ́sérẹrẹ nítorí àwọn èwẹ lójọ́ iwájú
Bó ṣẹ rẹrẹ, bó ṣẹ rẹrẹ oo
Bá'sìkò bá tó Olúayé fújì mi bó màá báyé ti ẹ lọ
Ẹré sún síwájú kò fìgbà kan dúró o
Èyàn tó bá bókọ̀ yí dájú dájú, la ó jọ gúnlè sí èbúté ayò oo
Èmi ló ni fújì mi
Torí onílú ò ní fé o tú
Ìgbà kań lọ ìgbà kán bọ̀ ọjọ́ gun óri ọjọ́
Gbogbo ìgbà kí gbà tó bá dẹ
Ìlàyí ẹlédùmarẹ̀ jé kó bá wa lára mu
Ẹkú àtijọ sè daadaa ni
Ẹkú àtijọ sè daadaa ni
Sé àlááfíà lẹ wà, gbogbo ilé ńkọ́ o
Ẹkú àtijọ sè daadaa ni
Ẹkú àtijọ sè daadaa ni
Sé àlááfíà lẹ wà, t'aya t'ọmọ ńkọ́ o
Ìsé tó ṣé ọmọ fún ogún ọdún
Ìyà tó jẹ ọmọ jẹ ọmọ fún osù méfà o
Bí o bà pa ọmọ à sí léyìn ọmọ ni
Mé lẹ nìkàn sé o
Mé lẹ nìkàn sé o
Mé lẹ nìkàn sé ilé ayé oo
Mé lẹ nìkàn sé ilé ayé
Ta da dan ta da
Pa ra ra pam pam, pa ra ra pam pam pam
Ton ton ton ton ton ton ton ton
Mé lẹ nìkàn sé ilé ayé
No one than God
Àwa dédédédé dé àwadé
Àwa lá ń kọ́ ọmọ lédè àwadé
Àwa dédédédé dé àwadé
Àyìndé lá ń kọ́ ọmọ lédè àwadé
Ọmọ ẹni o sẹ ìdí bèbèrè
Àkaǹké adé mi Melissa
Ká fi ìlèkè sí ìdí ọmọ èló mì
Àyìndé Wàsíù tẹni n tẹni tẹni n tẹni
Bá n dá kàsà f'ọ́mọ Anífowósẹ
Bá n dá kàsà f'ọ́mọ Anífowósẹ
Bá n dá kàsà kàsà kàsà kàsà kàsà f'ọ́mọ Anífowósẹ
Mé lẹ ṣáì jó fújì
Torí àlùjó pọpu níbè (Mé lẹ ṣáì jó fújì)
Mé lẹ ṣáì jó fújì o
Mé lẹ ṣáì jó fújì
Torí àlùjó pọpu níbè (Mé lẹ ṣáì jó fújì)
Written by: Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
instagramSharePathic_arrow_out