Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Islambo
Background Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Oluwaseun Opeyemi Olajuwon
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Citiboi
Producer
SKUCHIES MIX
Mastering Engineer
Lyrics
[Verse 1]
O n lọ e pe e pada
Ọba Idan ni ẹ pe ni Peller
Agba ni Metusela
Blow my trumpet and vuvuzela
Zuzubu zaba diko
Ṣo bowode ka ma niṣo
Patiently sabali
Kẹni binu o mu ganmọle
Ohun ọ mi o to ma naga
Ẹyin ṣi n fi gọgọ fa
Aye n yi bi jangilova
Ọrẹ
Pariwo oṣo niwọnba
[Chorus]
Ko si ninu iwe Kolose
Pe wọn ṣi ma fa Colos
Lo mu ekelebe smile bo ri ote
When I'm high a le pade loke
Talo wa ni agility mi o yi to?
To lọ n fẹjẹ we pito
Fẹnu ja o n ṣe Casamigos
Gba coin Taraba wọ Jalingo
[Chorus]
Ko si ninu iwe Kolose
Pe won ṣi ma fa Colos
[Verse 2]
Iwọ n ṣọkọ Rebe'
Nibi ti awọn kan ti n fo ferese
Jọ ba mi gbo Orin Dafidi
Mi o tọrọ idariji
Dẹrẹnrẹn, o Darlington
Ile-aye ni vanity
O ṣe
House party wọn play house music
Log drum Amapiano extra shit
Wọn fẹ tu bi aṣiri
A n miri si Amiri yin
Yo dara fun ọ
Omo igbala ṣe hallelu
Nibi ti a ti n mezebu
Pade mi loke Agelu
[Bridge]
House party wọn play house music
Log drum Amapiano extra shit
Wọn fẹ tu bi aṣiri
A n miri si Amiri yin
[Chorus]
Ko si ninu iwe Kolose
Pe wọn ṣi ma fa Colos
Lo mu ekelebe smile bo ri ote
When I'm high a le pade loke
Talo wa ni agility mi o yi to?
To lọ n fẹjẹ we pito
Fẹnu ja o n ṣe Casamigos
Gba coin Taraba wọ Jalingo
[Outro]
Nibo
Written by: Oluwaseun Opeyemi Olajuwon