Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Composer

Lyrics

[Verse 1]
Solo Makinde oo
Maa gbọ bi mo ṣe n wi, maa gbọ bi mo ṣe n forin lulu sọ
Solo Makinde oo
Solo Makinde
[Verse 2]
Ẹni tori ba ti da o, ori ti dayẹn na
Ẹni tori ba ti da o, ori ti dayẹn na
Ẹ ye lepa kadara, béèyàn kan lepa kadara lasan aṣọ rẹ a faya ni
O gbọ bi mo ṣe n wi, Ọmọgbọlahan Ayinde
Oluaye fuji mi o
[Verse 3]
Solo Makinde oo
Atẹwọ mo ba ila yii o, mi o mọ ẹni to kọ ọ, Ọmọgbọlahan Ayinde
Kaluku lo mori wa ile-aye
Ori kaluku yatọ
Ẹ ma fori Tayelolu kẹ fi we ti Kehinde o
Iya ibeji to bi wọn oun gan-an gan-an ti mọ
Pe kaluku lo mori ẹ wa
Ẹ ma fori adifa kẹ fi we t'adẹkun, Ayinde Ọmọgbọlahan, Ayinde
[Verse 4]
Atẹwọ mo ba ila yii o, mi o mẹni to kọ ọ, Ọmọgbọlahan Ayinde
Abi o gbọrọ mi o
Adio Monsuru mi o, ọmọ Onikoyi ni ilu Texas
Maa gbọ bi mo ṣe n wi
Alade Anuga mi o, Latunji Lukmon Alade
Ọkọ Monisola abi o gbọrọ mi gan-an
Mr. Toto Anuga Alade
[Verse 5]
Ẹni tori ba ti da o, ori ti dayẹn na
Ẹ ye lepa kadara, béèyàn kan lepa kadara lasan aṣọ rẹ a faya ni
Ọrọ ile-aye o toju su mi o
Ẹlẹnu pupọ ṣa laye, ẹnu t'ọn fi n pe adegun l'ọn fi n sọ pe ade o gun
Abi o gbọrọ mi gan-an
Hennesy ma gbọrọ mi o
Monsuru baby lawyer mi o ninu Chicago
[Verse 6]
Maa gbọ mi Basira Jọkẹ
Jọkẹ ọmọ Ṣogunro
Aya Tekane mi o ṣeun
Mother Alhaji, Alhaji mi o
Ma ma wolẹ o ṣeun
Awo Kẹmi baby Kẹmo Olukoya o ni New York City o
Mother Bobo mi o ṣeun
[Verse 7]
Nipa awọn olofofo t'ọn jẹ Solo Makinde
Ki lo n jẹ Solo Makinde o?
Awọn olofofo adugbo ni
Solo Makinde
Ofofo o gbẹgbaa ibi ọpẹ lo mọ
Solo Makinde ta lo fiṣẹ ran an yin?
Eke ile, Solo Makinde
[Verse 8]
Ki lo n jẹ Solo Makinde?
Isọwọ olofofo
Eke adugbo ni lo n jẹ Solo Makinde
Abẹnugu bẹ pati
Olofofo
Solo Makinde, a wa yin dele
A o ba yin nile
Ọmọ yin la ba to n j'Ojuyọbọ
Atẹwọ loju wa Ayinde, eyes kongba
[Verse 9]
Bẹ ba sọ fun wọn tẹ o gbọ o
Wọn tun lorukọ keji o
Eyi to lọ jọkunrin ninu Solo Makinde
Yaya lo n jẹ
Eyi to ba jobinrin ninu Solo Makinde
Lo n jẹ Deborah Ayinde, eyes kongba
[Verse 10]
Bẹ ba ri wọn lọna ẹ wo wọn re
Ẹni ta o fiṣẹ ran to lọ n toju bọle ka
Eke ile, Solo Makinde
[Verse 11]
Solo Makinde, eke yin
Awa yin dele a o ba yin nle
Ọmọ yin la ba to n j'Ojuyọbọ
Ofofo loju wa Ayinde, awọn eyes kongba o
[Chorus]
B'ọn pe mi lagbo fuji ma ya lọ (Ma jo, ma yọ)
B'ọn pe mi lagbo fuji ma ya lọ (Ma jo, ma yọ)
Ma jo ma yọ (O ya ma jo, ma yọ)
Ma jo ma yọ (O ya ma jo, ma yọ)
B'ọn pe mi lagbo fuji ma ya lọ (Ma jo ma yọ)
Ma tẹ Versace mi si (Ma jo ma yọ)
Instantly, instantly mafia (Ma jo ma yọ)
Ma jo ma yọ (Ma jo ma yọ)
Dolce Gabbana o ti lọ (Ma jo ma yọ)
Instantly, instantly mafia (Ma jo ma yọ)
Ma tun tẹ Versace mi si (Ma jo ma yọ)
[Chorus]
Ma ranju mọ mi mọ (Solo Makinde)
Ma ranju mọ mi mọ (Solo Makinde)
Iwọ nikan kọ lo loju (Solo Makinde)
Eke yin (Solo Makinde)
A wa yin dele (Solo Makinde)
A o ba yin nle (Solo Makinde)
Ọmọ yin la ba (Solo Makinde)
Written by: Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
instagramSharePathic_arrow_out