Lyrics
[Intro]
(No one is sleeker)
[Verse 1]
Wọn ni "Ki n wa baba to sabi"
Ko wa wori mi, k'ọn to sa si
Ki n ma ṣe yawo lọwọ Lati
Mo morin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
Wọn ni "Ki n wa baba to sabi"(Ehn ehn ehn)
Ko wa wori mi, k'ọn to sa si (Uhn uhn uhn)
Ki n ma ṣe yawo lọwọ Lati
Mo morin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
[Verse 2]
Ah, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan, o bomi si garri
O wọ Yankee, o wọ Atlanta, per roof
Eeyan Baba Fela ni, kẹ gba fun un
Ah, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan, o bomi si garri
O wọ Yankee, o wọ Atlanta, per roof
Eeyan Baba Fela ni, kẹ gba fun un
[Verse 3]
Uhhn, ki lo de o jere?
Mo ma jaye mi k'ọn to fun fere o
O ṣe, o ṣe, o ṣe o jere o
Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma kore oko dele o
Wọn gunyan mi kere o
Mo fimu wọn fọn feere oh
Ninu aye, mi o kere
To ba de igboro, ko lọ beere o
[Verse 4]
Wọn ni "Ki n wa baba to sabi"
Ko wa wori mi, k'ọn to sa si
Ki n ma ṣe yawo lọwọ Lati
Mo morin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
Wọn ni "Ki n wa baba to sabi"(Ehn ehn ehn)
Ko wa wori mi, k'ọn to sa si (Uhn uhn uhn)
Ki n ma ṣe yawo lọwọ Lati
Mo morin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
[Verse 5]
Ah, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan, o bomi si garri
O wọ Yankee, o wọ Atlanta, per roof
Eeyan Baba Fela ni, kẹ gba fun un
Ah, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan, o bomi si garri
O wọ Yankee, o wọ Atlanta, per roof
Eeyan Baba Fela ni, kẹ gba fun un
[Verse 6]
Uhhn, ki lo de o jere?
Mo ma jaye mi k'ọn to fun fere o
O ṣe, o ṣe, o ṣe o jere o
Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma kore oko dele o
Wọn gunyan mi kere o
Mo fimu wọn fọn feere oh
Ninu aye, mi o kere
To ba de igboro, ko lọ beere o
[Outro]
I will exalt you, Lord
For you have lifted me out
Has not let my foes to rejoice over me
(Timi Jay on the track)
Written by: Akinbiyi Ahmed Abiola, Aloba Ilerioluwa Oladimeji