Featured In
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
MohBad
Vocals
Zlatan
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Aloba Ilerioluwa Oladimeji
Songwriter
Omoniyi Temidayo Raphael
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Chech
Producer
Medua
Producer
Lyrics
[Intro]
Account balance lo jẹ ki n maa buga bayii
Ah backward never
Naira yatọ si cefa
Imọlẹ zaku na lamba
Imọlẹ
[Verse 1]
Apa ti jabọ o Jesu
Awọn kan lọ fori fogo
Ẹ wa wo cause trouble ye o
O ti ko sinu wahala t'awa
Apa ti jabọ ye o
Awọn kan lọ fori fogo ye o
Ẹ wa wo cause trouble ye o
O ti ko sinu wahala t'awa
[Verse 2]
Apa ti jabọ o Jesu
N gbọ ki lo gbe wa s'ori table?
O ja wire o ja cable
Ẹni o lowo lọwọ na disable
Gucci o yatọ si bata Jesu
Overconfidence o maa n jọ aṣeju
Ice lọrun mi o leku
Aṣiwaju bi Tinubu
[PreChorus]
Sunday o dagboru mọ bayii
Owo ni Monday mi n wa bayii
Ọmọ Alfa gan-an o ji mọ
Awọn NEPA gan-an o ni ina
[Chorus]
Account balance lo jẹ ki n maa buga bayii
Ah backward never
Naira yatọ si cefa
Imọlẹ zaku na lamba
[Verse 3]
Ku'o n'bẹ sẹ
Impossibility
Ọta mi o ni bori
Abi eni lẹ ti n gbọ ọ ladugbo yin?
Swaggu dripping, ọrun blinging
Mo ti lọmọ kan ladugbo yin
Gbagbe Island lọ beere n Mainland
Ja wọ anywere to ba yọ paper
Ọmọ ale lo ma ko ti'le ta
F'ẹyin ti o ye o maa ye e yin later
Imọlẹ o kuku bọlẹ
Eku ni wọn sẹ, wọn maa jẹ sọlẹ
Basket no fit fetch water like bucket
I be the plug sẹ
[PreChorus]
Sunday o dagboru mọ bayii
Owo ni Monday mi n wa bayii
Ọmọ Alfa gan-an o ji mọ
Awọn NEPA gan-an o ni ina
[Chorus]
Account balance lo jẹ ki n maa buga bayii
Ah backward never
Naira yatọ si cefa
Imọlẹ zaku na lamba
[Verse 4]
1 2 3 o maa fọ
Ẹni loyun lo maa sọ ọ
Ẹni bimọ ọran lo maa pọn
Lamba to dun wọn ni le kọ ọ
Awa o gbọ nnkan kan
Oju wa o fọ but a o ri nnkan kan
Pa show n Naija, pa show n London
A tun lẹnu pọn pọn pọn
[Verse 5]
Apa ti jabọ o Jesu
Awọn kan lọ fori fogo
Ẹ wa wo cause trouble ye o
O ti ko sinu wahala t'awa
Apa ti jabọ ye o
Awọn kan lọ fori fogo ye o
Ẹ wa wo cause trouble ye o
O ti ko sinu wahala t'awa
[PreChorus]
Sunday o dagboru mọ bayii
Owo ni Monday mi n wa bayii
Ọmọ Alfa gan-an o ji mọ
Awọn NEPA gan-an o ni ina
[Chorus]
Account balance lo jẹ ki n maa buga bayii
Ah backward never
Naira yatọ si cefa
Imọlẹ zaku na lamba
Written by: Aloba Ilerioluwa Oladimeji, Omoniyi Temidayo Raphael, Writer Unknown