Credits
PERFORMING ARTISTS
MohBad
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Aloba Promise Oladimeji
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Niphkeys
Producer
Lyrics
[Intro]
Niphkeys
Imọlẹ, o walẹ jọ
[PreChorus]
If I dey play football, I go bench Messi
Bench Neymar
Bench Ronaldo oh
Ti n ba fẹ gbọmọ, mo ma gbe Eminado
No shepeteri
No shakushaku oh
[Chorus]
Ani sẹ o
Wọn le-le-le-le-le-le-le-le, wọn o ba
Wọn wa-wa-wa-wa-wa, wọn o ma ri o
Wọn le-le-le-le-le-le-le-le, wọn o ba
Wọn wa-wa-wa-wa-wa, wọn o ma ri o
[Verse 1]
Abẹrẹ ma lọ, kọna okun to di
O doju ala, ka to rira wa
Abẹrẹ ma lọ, kọna okun to di oh-oh-oh
O doju ala, ka to rira wa
Ẹmi mimọ ti cover mi
Anything o le bother mi
Ma l'owo, ma ni motor oh
Ẹmi mimọ ti cover mi
Anything o le bother mi
Emi ti l'owo, mo dẹ ti ni motor oh, ah
[PreChorus]
If I dey play football, I go bench Messi
Bench Neymar
Bench Ronaldo oh
Ti n ba fẹ gbọmọ, mo ma gbe Eminado
No shepeteri oh
No shakushaku oh
[Chorus]
Ani sẹ o
Wọn le-le-le-le-le-le-le-le, wọn o ba
Wọn wa-wa-wa-wa-wa, wọn o ma ri o
Wọn le-le-le-le-le-le-le-le, wọn o ba
Wọn wa-wa-wa-wa-wa, wọn o ma ri o
[Verse 2]
Ariya-ya-ya-ya-ya ti ya oh-oh
O n dun wọn, o n ka wọn lara
Bi mo ṣe n ṣiṣẹ mi, mo n gbowo mi, mo n jaye mi
O n dun wọn, o n ka wọn lara
Ah, fire, fire for my body
Emi ti mọ awọn ọmọ oshosondi
Awọn ọmọ to lowo lọwọ awọn ọmọ lotto
Fire, fire for my body
Emi ti mọ awọn ọmọ oshosondi
Awọn ọmọ to lowo lọwọ, ajinomoto oh, ah
[PreChorus]
If I dey play football, I go bench Messi
Bench Neymar
Bench Ronaldo oh
Ti n ba fẹ gbọmọ, mo ma gbe Eminado
No shepeteri oh
No shakushaku oh
[Chorus]
Ani sẹ o
Wọn le-le-le-le-le-le-le-le, wọn o ba
Wọn wa-wa-wa-wa-wa, wọn o ma ri o
Wọn le-le-le-le-le-le-le-le, wọn o ba
Wọn wa-wa-wa-wa-wa, wọn o ma ri o
[Outro]
Timi Jay on the track
Written by: Aloba Promise Oladimeji