Featured In
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
MohBad
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Aloba Ilerioluwa Oladimeji
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Niphkeys
Producer
Nektunez
Producer
Lyrics
[Chorus]
Ask about me, ask about me ('Bout me)
Wọn ti le mi, but wọn mu mi
Ọmọ Ọlọrun, ko le su mi
Seke-sekebula ('bula)
I'm still getting my mula
Dollar pẹlu naira
Iku to pa iya teacher (Teacher), o le pa awọn ****
Kí ló ń fó lókè oh? (Fó lókè)
Ẹyẹ ló ń fó lókè oh (Fó lókè)
Kí ló ń rìn ni'lẹ? (Rìn ni'lẹ)
Àwọn èèyàn ló má ń rìn ni'lẹ, ma tẹ mi mo'lẹ, oh-oh
Má tẹ ojú ilẹ mọ'lẹ, ko máà bà dọbalẹ
Ìwọ lo ma f'Èkó lẹ, ko f'Èkó lẹ fún awa soldier
Mẹta-mẹta, gbosa
Awilo Logomba, fún mi l'owó mí biza
Kese-kese, kasa, Casa-Casablanca
I open Bible Chapter, I stepped on the Satan
Mó p'èṣù dànù, mo kan l'ẹsẹ kan
O tamurege, Jigan, oh-oh, why? Oh-oh, why?
[Verse 1]
They don't know, they don't know
They don't know, they don't know I don go (They don't know)
They wan' know, they wan' know
They wan' know, they wan' know where I'm going (I don go)
Kí ló fa frapapapa? Kí ló fa pattern yẹn?
Wọn fẹ ká mi mọ 'bẹyẹn
Ọpọ́n ti sún finally, ọpọ́n ti sún finally
A ò bẹlẹnu méjì ṣeré mọ
[Chorus]
Ask about me, ask about me
Wọn ti le mi, but wọn mu mi
Ọmọ Ọlọrun, ko le su mi
Seke-sekebula
I'm still getting my mula
Dollar pẹlu naira (Naira)
Iku to pa iya teacher (Teacher), o le pa awọn ****
Kí ló ń fó lókè oh? (Fó lókè)
Ẹyẹ ló ń fó lókè oh (Fó lókè)
Kí ló ń rìn ni'lẹ? (Rìn ni'lẹ)
Àwọn èèyàn ló má ń rìn ni'lẹ, ma tẹ mi mo'lẹ, oh-oh
Má tẹ ojú ilẹ mọ'lẹ, ko máà bà dọbalẹ
Ìwọ lo ma f'Èkó lẹ, ko f'Èkó lẹ fún awa soldier
Mẹta-mẹta, gbosa
Awilo Logomba, fún mi l'owó mí biza
Kese-kese, kasa, Casa-Casablanca
I open Bible Chapter, I stepped on the Satan
Mó p'èṣù dànù, mo kan l'ẹsẹ kan
O tamurege, Jigan, oh-oh, why? Oh-oh, why?
Written by: Aloba Ilerioluwa Oladimeji