Featured In
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
MohBad
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Aloba Promise Oladimeji
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Niphkeys
Producer
Lyrics
(Niphkeys, Niphkeys)
Imọlẹ
Plenty enemy (Mohbad)
Wey dey follow me
Ma jẹ k'ọn mu mi
Even if na dying minute
Emi ọmọ ghetto
Mo ti d'aji lo motor (mo ti d'aji lo motor)
My grace na auto, automatic
Wọn fẹ ba mi ya photo (photo)
Emi ti gbera (on God)
Lati 4:30 (on God)
Wọn le, wọn ba ti (on God)
Wọn mu, wọn filẹ (on God)
I drip on check, o tu wa on point
Imọlẹ (on God)
O wa'lẹ (on God)
(On God)
Ahn, when I dey Ikorodu, sapa mu mi
Mo ma ronu
Mo ma sunkun (mo ma sunkun)
Ehn, I don work tire
I don pray tire
I don go Mountain of Fire, ah
I know there is a day
All my pains will go away
'Til then, I'll party away
I know there is a day
All my pains will go away
'Til then, I smoke it away
I feel good, pa, ran-ran, pa, ran-ran
Ọmọ iya mi, ma lọ ronu o, ko pa, ran-ran, pa, ran-ran
I feel good (pa, ran-ran)
Emi ọmọ ghetto (emi ọmọ ghetto)
Mo ti d'aji lo motor (mo ma ti d'aji lo motor)
My grace na auto, automatic
Wọn fẹ ba mi ya photo (photo)
Emi ti gbera (on God)
Lati 4:30 (on God)
Wọn le, wọn ba ti (on God)
Wọn mu, wọn filẹ (wọn mu, wọn filẹ) (on God)
I drip on check, o tu wa on point
Imọlẹ (on God)
O wa'lẹ (on God)
(On God)
Imọlẹ, o wa'lẹ
Bo ṣe n mulẹ, lọ ṣe n jẹ
Lat'aye tipẹ-tipẹ
Imọlẹ, o wa'lẹ
Bo ṣe n mulẹ, lọ ṣe n jẹ
Lát'aye tipẹ-tipẹ
Plenty enemy
Wey dey follow me
Ma jẹ k'ọn mu mi
(Imọlẹ)
(Timi Jay on the track)
Writer(s): Ilerioluwa Aloba, Oluwanifemi Adebajo
Lyrics powered by www.musixmatch.com