Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
MohBad
MohBad
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Aloba Ilerioluwa Oladimeji
Aloba Ilerioluwa Oladimeji
Songwriter
ADEYEMI OLANREWAJU ABRAHAM
ADEYEMI OLANREWAJU ABRAHAM
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
larrylanes
larrylanes
Producer

Lyrics

[Intro]
Everyday for the thief, one day for the owner
Wọn ti ṣojoro oh
Wọn ti ṣojoro
Imọlẹ
Uhn-uh
[Verse 1]
Ṣebi ajọṣe Marlians ni
Wọn wa fẹ ma corner mi (Wọn parọ)
Wọn tun fẹ bother mi (I get the padlock)
But, Oluwa cover mi (Uh-uhh)
Wọn pe daddy mi (Wọn pe daddy)
Wọn threaten mummy mi
They wan take the peace in me (Ohh)
Wọn fẹ mo Ọlọhun mi
Ararara-ra-ra, ara, ara
Wọn ti ṣojoro, ara, ara
Ararara-ra-raa, ara, ara
Wọn ti ṣojoro (Wọn ti ṣojoro)
I no go gree, oh-no
[Chorus]
Everyday for the thief, one day for the owner
Paso Wonder, fuck their Gunner
Emi Messi, I no be loser
Wọn fẹ ki Ronaldo gba corner
Barcelona, for the corner
Mm, wọn fẹ ki n wọ sapa
I don stop to smoke ganja
Mo dupẹ f'Oluwa, Hallelujah
[Verse 2]
Zee, ko ja
Black, MohBad
Dollar, mo rise
Why is naira going down?
Ko si much but mo guide
Mi o fresh but mo fine
Wọn riran, mo sight
In darkness, I'm the light
[Chorus]
Everyday for the thief, one day for the owner
Paso Wonder, fuck their Gunner
Emi Messi, I no be loser
Won fe ki Ronaldo gba corner
Barcelona, for the corner
Mm, won fe kin wo sapa
I don stop to smoke ganja
Modupe f'Oluwa, Hallelujah
[Verse 3]
Ọrọ kan n gbe mi lọkan
Ẹ bẹ mi make I shut up (Ẹ bẹ mi, ẹ bẹ mi)
Mm, 'cause mo fẹ sọrọ kan (Mo fẹ sọrọ, mo fẹ sọrọ)
But, appreciation pọ gan-an
Fun awọn to da mi mọ
Mo tun mọ'yan gan-an
Mm, Naira
Everyday for the thief, one day for the owner
Everyday for the thief, one day for the owner
Everyday
Written by: Adeyemi Abraham, Aloba Ilerioluwa Oladimeji
instagramSharePathic_arrow_out