Top Songs By Agaga
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Agaga
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Agaga Olamide obey
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Elelpdbeat
Producer
Lyrics
Agaga ga more re o
Alagbe kilode oo?
Anlo sori oke agbedu
Gbera o
Sebi ó ni kosi ibiti Olorun osi
Ankara moni Gucci ni osi
ATM wa owo ni osi o
Majè kómó Olórun mi kusi inu osi o
Toba jè awón tobi mi lofori pe egun laye ójó un ni
Mo jaa
Bojè mama mi
Mo jaa
Bojè baba mi
Mo jaa
Bojè awón to sunmó mi
Mo jaa
Jakiri jaa jaa jaa
Bojè iyawo mi
Mo jaa
Abómo ti mo nba sun
Mo jaa
Ibitoti gbebi mi
Mo jaa
Tabi omi tofi wé mi ni
Jakiri jaa jaa jaa
Baba mi ti se won ri se
Iyami ti se won ri se
Awón ebi mi se won ri se
Lasiko temi jè n ri se
To Holy ghost mi ba ti fire tan
Owo ni ko bami wire na
To owo ba wole komasi agbana
To ogo mi ba de ko ma di taana o
Imólè mi se èru ba okunkun wón
Kalaba fè ojuju wón
Toba jè awón tobi mi lofori pe egun laye ójó un ni
Mo jaa
Bojè mama mi
Mo jaa
Bojè baba mi
Mo jaa
Bojè awón to sunmó mi
Mo jaa
Jakiri jaa jaa jaa
Bojè iyawo mi
Mo jaa
Abómo ti mo nba sun
Mo jaa
Ibitoti gbebi mi
Mo jaa
Tabi omi tofi wé mi ni
Jakiri jaa jaa jaa
Passport ti o ni visa ID card ni, Ólórun
Ówó ti o ka owo ri handicap ni, Ólórun o
Bèlé o lómó ani Bèlé o lómó
Bet naija la nri jè
Bet naija ta n ri jè gan wón pada jèwa
Saraabulihaimó
Ani Bèlé o lómó
Bet naija la nri jè,
Bet naija ta n ri jè gan wón pada jèwa
Saraabulihaimó, Elofirija Eloserini
Eri to wa lagelu lo wa lerimó Baba se iyanu laye mi
Asiko nlo
Sebi ó ni kosi ibiti Olorun osi
Ankara moni Gucci ni osi
ATM wa owo ni osi o
Majè kómó Olórun mi kusi inu osi o
Toba jè awón tobi mi lofori pe egun laye ójó un ni
Mo jaa
Bojè mama mi
Mo jaa
Bojè baba mi
Mo jaa
Bojè awón to sunmó mi
Mo jaa
Jakiri jaa jaa jaa
Bojè iyawo mi
Mo jaa
Abómo ti mo nba sun
Mo jaa
Ibitoti gbebi mi
Mo jaa
Tabi omi tofi wé mi ni
Jakiri jaa jaa jaa
Written by: Agaga Olamide obey