Featured In
Top Songs By Naira Marley
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Naira Marley
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Azeez Fashola
Lyrics
Chisom Ezeh
Composer
Lyrics
[Intro]
Ṣ'ọja le jeburẹ
Tabi ko jẹ chicken
Ah wa Kazeem
Ọja pada jẹ Kazeem
Ọlọhun ma jẹ n sinwin rara
[PreChorus]
If to say na madness (Madness)
If to say na craze (Say na craze)
Ọlọhun ma jẹ n sinwin rara (ọlọhun ma jẹ n sinwin)
Baba ma ya mi n'were (Baba ma ya mi n'were)
Ọja ma jẹ mi (Ọja ma jẹ mi)
Don't dare my best friend (My dear my best friend)
Jẹ ki n le gbẹsẹ (Jẹ ki n le gbẹsẹ)
Jẹ ki n rọwọ gbe
[Chorus]
Ọja to j'ọmọ ọlọja (Ọja)
Ọja lo jẹ o jawo ọja (Ọja)
Tọja ti tẹlẹ pẹpẹ (Ọja)
Tọja ti tẹlẹ sara (Ọja)
Ọja lo n ba wọn ja (Ọja)
Ọja lo ko wọn jiya (Ọja)
Ọja i jẹni ba jẹ ọja mi o ta gamble ọja ma jẹ mi na (Ọja)
[Bridge]
Ọlọhun ma jẹ n sinwin rara
Baba ma ya mi n'were
Ọlọhun ma jẹ n sinwin rara
Baba ma ya mi n'were
[PreChorus]
If to say na madness (Madness)
If to say na craze (Say na craze)
Ọlọhun ma jẹ n sinwin rara (Ọlọhun ma jẹ n sinwin rara)
Baba ma ya mi n'were (Baba ma ya mi n'were)
Ọja ma jẹ mi (Ọja ma jẹ mi)
Don't dare my best friend (My dear my best friend)
Jẹ ki n le gbẹsẹ (Jẹ ki n le gbẹsẹ)
Jẹ ki n rọwọ gbe
[Chorus]
Ọja to j'ọmọ ọlọja (Ọja)
Ọja lo jẹ o jawo ọja (Ọja)
Tọja ti tẹlẹ pẹpẹ (Ọja)
Tọja ti tẹlẹ sara (Ọja)
Ọja lo n ba wọn ja (Ọja)
Ọja lo ko wọn jiya (Ọja)
Ọja i jẹni ba jẹ ọja mi o ta gamble ọja ma jẹ mi na (Ọja)
Written by: Azeez Fashola, Chisom Ezeh