Lyrics
Agogo kò ro,agogo kò má ro (agogo kò má ro)
Agogo kò ro,agogo kò má ro (agogo kò má ro)
Torí ibadi ni ijó wá
Ojú sá là fi nri ìran,ọwọ' la fi ń júwe Ayinde mo tún dè
Olú ọmọ federation,ijó ń bẹ ìyẹn ẹwẹ nẹ
Ijó ń bẹ ìyẹn ẹwẹ nẹ,ijó ń bẹ ìyẹn ẹwẹ nẹ (ijó ń bẹ ìyẹn ẹwẹ nẹ)
Àní,ijó ń bẹ ìyẹn ẹwẹ nẹ (ijó ń bẹ ìyẹn ẹwẹ nẹ)
Mo ni ijó ń bẹ ìyẹn ẹwẹ nẹ (ijó ń bẹ ìyẹn ẹwẹ nẹ)
Bó bá ṣe sí mi ọmọ tó gbolahan,ma fọgbọ́n ta ẹ yọ (ma fọgbọ́n ta ẹ yọ)
Bo tun ṣe simi bo di ẹlẹnkeji,ma fọgbọ́n ta ẹ yọ (ma fọgbọ́n ta ẹ yọ)
Bo bá tá sì mi ọmọ tó gbolahan,ma fọgbọ́n ta ẹ yọ (ma fọgbọ́n ta ẹ yọ)
Mo ṣepé-ṣepé,mo ṣepé-ṣepé (mo ṣepé-ṣepé)
Mo ṣepé-ṣepé,mo ṣepé-ṣepé (mo ṣepé-ṣepé)
Ṣe pé ò,ṣe pé o,ṣe pé ó
Mo ṣepé-ṣepé,mo ṣepé-ṣepé (mo ṣepé-ṣepé)
Ṣe pé tí mò wí olú ọmọ federation lafi fọgbọ́n tá wọn yọ
Ẹ má ro wipé yẹyẹ l'ọrọ' mi ò,ìyá ń ronú ọmọ ń roka
Òní ohun tó bá kaluku,sebi orin fuji ló bá mi ẹgbo mi yé
Èwo ni ká joyè àwòdì ka ma lè gbé ẹdìyẹ
Ọba fuji lon bọ (ọba fuji lon bọ)
Èwo ni ká joyè àwòdì ka ma lè gbé ẹdìyẹ
Ọba fuji lon bọ (ọba fuji lon bọ)
Ba rẹ ní ti oba mọ mí ẹso fún kò lọ gbé iná wá
Ko wá wo Ayinde Ade ọba fuji ló ń bọ' (ọba fuji lon bọ)
Ba rẹ ní ti oba mọ mí ẹso fún kò lọ gbé iná wá
Ko wá wo Ayinde Ade ọba fuji ló ń bọ' (ọba fuji lon bọ)
Mo ṣepé-ṣepé,mo ṣepé-ṣepé (mo ṣepé-ṣepé)
Ṣíṣí mi,mo ṣepé-ṣepé,mo ṣepé-ṣepé (mo ṣepé-ṣepé)
Pé ò,pé o,pé ó
Mo ṣepé-ṣepé (mo ṣepé-ṣepé)
Ṣe pé tí mò wí olú ayé fuji lafi fọgbọ́n tá wọn yọ (lafi fọgbọ́n tá wọn yọ)
Bẹ bínú bínú hún ó má re àdúgbò mi o
Hún ó má re àdúgbò mi o (hún ó má re àdúgbò mi o)
Àní bẹ bínú bínú hún ó má re àdúgbò mi o
Hún ó má re àdúgbò mi o (hún ó má re àdúgbò mi o)
Hún ó má re àdúgbò mi o (hún ó má re àdúgbò mi o)
Ibo la àdúgbò mí,agarau,Ìsàlẹ' èkó,Ìsàlẹ' ọ'fín,òkè pò pọpó,ẹpẹtẹdo dé Lafiaji olú ọmọ federation
Lafi fọgbọ́n tá wọn yọ (lafi fọgbọ́n tá wọn yọ)
Àní bẹ bínú bínú hún ó má re àdúgbò mi o
Hún ó má re àdúgbò mi o (hún ó má re àdúgbò mi o)
Hún ó má re àdúgbò mi o (hún ó má re àdúgbò mi o)
T'ori gbogbo àsà tí ń ba da,Ayinde mi Gbolohan ó kẹ dẹ ni reason
Ani gbogbo àsà tí ń ba da,Ayinde mi Gbolohan ó kẹ de ni reason (ó kẹ dẹ ni reason)
Ó kẹ dẹ ni reason (ó kẹ dẹ ni reason)
Ó kẹ dẹ ni reason (ó kẹ dẹ ni reason)
Mọ ni gbogbo àsà tí ń ba da,Ayinde mi Gbolohan ó kẹ dẹ ni reason (ó kẹ dẹ ni reason)
Golobà lọ ń bọ' ó,golobà lọ ń bọ' ó (golobà lọ ń bọ' ó)
Golobà lọ ń bọ' ó,golobà lọ ń bọ' ó (golobà lọ ń bọ' ó)
Golobà lọ ń bọ' ó,golobà lọ ń bọ' ó (golobà lọ ń bọ' ó)
Ọ'rọ' to wá nilẹ yí,ẹni ba lo mo ó
Gbogbo ọ'rọ' to wá nilẹ yí,ẹni ba lo mo ó
Ọ'rọ' to wá nilẹ yí,ẹni ba lo mo ó
Gbogbo ọ'rọ' to wá nilẹ yí,ẹni ba lo mo ó
(Ni bo) (ni bo)
Written by: K1 De Ultimate