Credits
PERFORMING ARTISTS
Islambo
Background Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Oluwaseun Opeyemi Olajuwon
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Citiboi
Producer
SKUCHIES MIX
Mastering Engineer
Lyrics
[PreChorus]
Bọbọ Alaṣakaṣa yii
Ọkan daṣakaṣa ṣa!
[Chorus]
Oluwa lo kọla owo mi ko fi pele si
Ọba mi oke
Mo n ga mi o kere si
Janla ja lailu
Maa jo kukere si
Ma ra aṣọ tuntun lọjọ Keresi
[Verse 1]
Mo n gbe wọn lọ
Mo n gbe wọn mo n gbe wọn trabs
Mo n gbe wọn lọ
Gbe wọn debẹ mi o test drive
Mo n gbe wọn lọ
Mo n gbe wọn mo n gbe wọn trabs
Mo n gbe wọn lọ
Mo ti ṣigbo si pocket 5
[PreChorus]
Ọmọ ọlọdun yẹrawo
Na where gbadun dey me I go
Mo gbe sori bi pineapple
Igbadun maa n heal bi agbo
Hello story of a niqqa
Ina lo n lo kẹkẹ Elijah
Na aura be liver
Dispatch and deliver
Who's that?
Dispatcher
Oh sorry, I'm in the bathroom
Drop it at the doorstep
O da pe ẹ n vibe
No be only me dey feel am
Mo ri pe o gas
Ponponpon bila
Ṣo ri mustache
Herbert Marcu', cur
Ori lo mọ fa
O lọ far far
I'm classic and wobey
Tested and okay
Crazy melody
Ko si office like Opay
Fo silẹ, fo soke
They wonder where this boy dey see lamba like this
O pọ gan-an ni body
Lamba to high ju canabis
If Alisha no gree to kiss
I face my front ma lọ muti
Na why I dey road
Ọpa o pejo when your heart is so cold
Correct your typo
Activate your psycho
Romance your Bible
[PreChorus]
Oluwa lo kọla owo mi ko fi pele si
Ọba mi oke
Mo n ga mi o kere si
Janla ja lailu
Maa jo kukere si
Ma ra aṣọ tuntun lọjọ Keresi
Mo n gbe wọn lọ
Mo n gbe wọn mo n gbe wọn trabs
Mo n gbe wọn lọ
Gbe wọn debẹ mi o test drive
Mo n gbe wọn lọ
Mo n gbe wọn mo n gbe wọn trabs
Mo n gbe wọn lọ
Mo ti ṣigbo si pocket 5
Written by: Oluwaseun Opeyemi Olajuwon