Credits
PERFORMING ARTISTS
Rybeena
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Adewale Atanda
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
TBM
Producer
Lyrics
[Verse 1]
Mo gbe kelebe wọ club o mu Bellaire
La ba dele tan lo ba l'ọn ṣepo o
To ba jerekere stop mi o ba e fẹyin
Sare fun mi lori ọmọ time dey go
Don't please my heart, please my body
Ṣo mọ pọlọmọge yapa nigboro
I no fit lose my feeling for the Benjamin
You no fit enter me
[PreChorus]
Ṣo mọ iru **** mi? (Uhh uhh)
Ọmọ ko sija ni church ṣadura ki n ṣami (Uhh uhh)
Ọmọ ọpẹ no fit give up ko ṣa ti ri lappy (Uhh uhh)
Ṣebi ọrẹ **** mi kan lo fi colo yi baki
Lo ba tun kigbe "gba mi, gba mi oo"
[Chorus]
Ẹ wa wo ole
Ajibole
O ni ko ki n ṣole
O ri lo gbe
Ẹ wa wo ole
Ajibole
O ni ko ki n ṣole
O ri lo gbe
[Refrain]
Iṣo, Baba Ruka
Eyin lo yọ, ẹmi o bọ
Iṣo, Baba Ruka
Eyin lo yọ, ẹmi o bọ
[PreChorus]
Ṣo mọ iru **** mi? (Uhh uhh)
Ọmọ ko sija ni church ṣadura ki n ṣami (Uhh uhh)
Ọmọ ọpẹ no fit give up ko ṣa ti ri lappy (Uhh uhh)
Ṣebi ọrẹ **** mi kan lo fi colo yi baki
Lo ba tun kigbe "gba mi, gba mi oo"
[Chorus]
Ẹ wa wo ole
Ajibole
O ni ko ki n ṣole
O ri lo gbe
Ẹ wa wo ole
Ajibole
O ni ko ki n ṣole
O ri lo gbe
[Refrain]
Iṣo, Baba Ruka
Eyin lo yọ, ẹmi o bọ
Iṣo, Baba Ruka
Eyin lo yọ, ẹmi o bọ
Written by: Atanda Adewale