Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
BhadBoi OML
BhadBoi OML
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Kuham Oladimeji Akinyinka
Kuham Oladimeji Akinyinka
Songwriter
Adeyemi Olanrewaju
Adeyemi Olanrewaju
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Damilola "Dapper" Akinwunmi
Damilola "Dapper" Akinwunmi
Executive Producer

Lyrics

[Intro]
Ọmọ ọla lele yii
Listen to the sound bending sound bender
Alade Ade
I don't really know what to talk about you
Ija lo de lorin d'owe o
Alade Ade
I don't really know what to say about you
[Verse 1]
Ọmọ I de try Alade I de try
Ko le kol e ẹ ẹ ri po n gun ọna ọfun
Omo I de try Alade I de try
Ko le kol e ẹ ẹ ri po tough
[Chorus]
Ma we yii o (Ma we)
Oluwe ma we yii o (Ma we)
Ma we yii o (Ma we)
Oluwe ma we yii o (Ma we)
[Verse 2]
Ẹ ma wẹyin o (Ma we)
Idi ọrẹ mi ni n o fi si o (Ma we)
Ẹ ma wẹyin o (Ma we)
Idi ọrẹ mi ni n o fi si o (Ma we)
[Verse 3]
Life is war, came with my ammunition
I bring sword I will never ever miss shot
Life is sure lo ṣe ma n ka mi niṣan
Life is sure lo ṣe ma n ka mi niṣan
[Verse 4]
Son of Adam, do you have a girlfriend?
Does she give you peace?
Does she give you kiss and less stress?
[Verse 5]
Ṣọmọ eku o ki n ke bi ọmọ eku
Abi ọmọ ẹran o ki n ke bi ọmọ ẹran
Most times, most times na money palava
Another time, most times na woman wahala
Edumare jẹ n jọba pẹ
Apẹkoto jẹun ṣi le j'ẹbajẹ
[Chorus]
Ma we yii o (Ma we)
Ni Mushin l'Olosha (Ma we)
Ma we yii o (Ma we)
Lẹgbẹ shop ọrẹ mummy mii (Ma we)
[Verse 6]
Ọmọ I de try, Alade I de try
K’ole K’ole eeri p’ogun ona ofun
Omo I de try Alade I de try
K’ole K’ole eeri pe o tough
[Chorus]
Ma we yii ooo (Ma we)
Oluwe ma we yii oo (Ma we)
Ma we yii oo (Ma we)
Oluwe ma we Yii oo (Ma we)
[Bridge]
Alade Ade I don’t really know what to talk about you
Ija lo de lorin d'owe o
Alade Ade I don’t really know what to say about you
[Outro]
Ẹ ma wẹyin o (Ma we)
Idi ọrẹ mi ni n o fi si o (Ma we)
Ẹ ma wẹyin o (Ma we)
Idi ọrẹ mi ni n o fi si o (Ma we)
Written by: Adeyemi Olanrewaju, Kuham Oladimeji Akinyinka
instagramSharePathic_arrow_out