Featured In
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Balloranking
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Balloranking
Songwriter
Lyrics
[PreChorus]
Zero pa' (Zero pa' oh), maga ti dawo
Na kontopia, Shakira dance Alanta
Rọra ṣe mi l'Oroma (Oroma oh)
Tori ẹ ni mo ṣe kọja (Kọja)
Ẹyin ibadi ẹ, koroba
Ifẹ rẹ, maami, lakọja oh, lakọja oh
[Chorus]
I stay woke, I don't wanna stay broke
L'Eko, were la fi n gb'Eko (Ah, l'Eko)
Melo melo ma lẹnu fẹ sọ? (Fẹ sọ)
I thank God, I made it to the top
I stay woke, I don't wanna stay broke
L'Eko, were la fi n gb'Eko (Ah, l'Eko)
Melo melo ma lẹnu fẹ sọ? (Fẹ sọ)
I thank God, I made it to the top
[Refrain]
Ọmọ t'ọn sọ, ọmọ to n ta
Jẹ ka pade l'Oriental (Ah, jẹ ka pade l'Oriental)
4310, Nokia oh
O jabọ, ko fọ, I don't care oh (I don't care)
V'20 na lockdown
Mo gbera tan oh, I don meow oh (Meow)
[Verse 1]
Fọ si wọn lara, tata-ta
Aṣọ iyi mi, ma ṣe faya
Amina dey gimme papapa
Say we dey give dem heart attack
I get Pluto oh
Paddie mi, wire crypto
Jaye bi ẹni jẹ lotto oh
O dijọ to ba fẹ morukọ owo, to ba fẹ morukọ owo
[PreChorus]
Zero pa' (Zero pa' oh), maga ti dawo
Na kontopia, Shakira dance Alanta
Rọra ṣe mi l'Oroma (Oroma oh)
Tori ẹ ni mo ṣe kọja (Kọja)
Ẹyin ibadi ẹ, koroba
Ifẹ rẹ, maami, lakọja oh, lakọja oh
[PreChorus]
I stay woke, I don't wanna stay broke
L'Eko, were la fi n gb'Eko (Ah, l'Eko)
Melo melo ma lẹnu fẹ sọ? (Fẹ sọ)
I thank God, I made it to the top
I stay woke, I don't wanna stay broke
L'Eko, were la fi n gb'Eko (Ah, l'Eko)
Melo melo ma lẹnu fẹ sọ? (Fẹ sọ)
I thank God, I made it to the top
[Refrain]
Ọmọ t'ọn sọ, ọmọ to n ta
Jẹ ka pade l'Oriental (Ah, jẹ ka pade l'Oriental)
4310, Nokia oh
O jabọ, ko fọ, I don't care oh (I don't care)
V'20 na lockdown
Mo gbera tan oh, I don meow oh (Meow)
[Verse 2]
Fọ si wọn lara, tata-ta
Aṣọ iyi mi, ma ṣe faya
Amina dey gimme papapa
Say we dey give dem heart attack
I get Pluto oh
Paddie mi, wire crypto
Jaye bi ẹni jẹ lotto oh
O dijọ to ba fẹ morukọ owo, to ba fẹ morukọ owo
[Outro]
This, is crazy
Written by: Balloranking