Featured In
Credits
PERFORMING ARTISTS
BhadBoi OML
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
BhadBoi OML
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Damilola "Dapper" Akinwunmi
Executive Producer
Lyrics
[Intro]
Ọrọ n gbenu mi sọrọ
Oṣa n gbenu mi fọhun
Sango n gbenu mi ṣo mọ?
Ẹluku n gbenu mi fọhun
[Verse 1]
And I no too like to dey vex
Ẹyin ẹlẹnu mẹta logo Benz
Pikin wey say him papa no go sleep, him mama no go vex
Many pepper no go rest ẹ gba bẹẹ
Chocolate and caramel (Oouuu wee)
Obi ati orogbo (Oouuu wee)
Ẹyin lẹ ma sin iya yin (Oouuu wee)
Oku o n sanwo posi, ṣo mọ? (Oouuu wee)
[Chorus]
Chocolate and caramel (Oouuu wee)
Ẹbu at'ogogoro (Oouuu wee)
Ọla n bi wọn ninu (Oouuu wee)
O n ka wọn lara (Oouuu wee)
[Verse 2]
Let's take it back to back good days, old days, those days tẹ n foribẹ
I told 'em, I told 'em, o n ja mi lara jẹ buh na tip of the iceberg
Aponle diẹ, diẹ, diẹ lara n fẹ
Afọṣẹ n bẹ to ba fẹ o ma lala ri were
Ṣọpọnna ni mi mo ni kẹ ma rin mi fin
It, it is what it is, me I kuku come in peace
Kilimanjaro lẹ n sọ fun pe arara o ga
Ẹ lọ sọ fun ọga yin pe Ọmọla sọ pe "Ori wọn o da"
Wọn le, wọn le, wọn le, wọn o ba
Wa wo Ronaldinho o ma mọ pe Messi gan-an o da
[Chorus]
And I no too like to dey vex
Ẹyin ẹlẹnu mẹta logo Benz
Pikin wey say him papa no go sleep, him mama no go vex
Many pepper no go rest ẹ gba bẹẹ
Chocolate and caramel (Oouuu wee)
Obi ati orogbo (Oouuu wee)
Ẹyin lẹ ma sin iya yin ((Oouuu wee))
Oku o n sanwo posi, ṣo mọ? (Oouuu wee)
[Chorus]
Chocolate and caramel (Oouuu wee)
Ẹbu at'ogogoro (Oouuu wee)
Ọla n bi wọn ninu (Oouuu wee)
O n ka wọn lara (Oouuu wee)
[Outro]
Chocolate and caramel (Oouuu wee)
Ẹbu at'ogogoro (Oouuu wee)
Ọla n bi wọn ninu (Oouuu wee)
O n ka wọn lara (Oouuu wee)
Written by: BhadBoi OML