Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
BhadBoi OML
BhadBoi OML
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
BhadBoi OML
BhadBoi OML
Songwriter
Saheeb Habeeb Daniel
Saheeb Habeeb Daniel
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Busy Pluto
Busy Pluto
Producer

Lyrics

[PreChorus]
No pain no gain
No name no fame, no face no case
Hallelujah meje at'abẹla meje fun ọjọ meje
Gudugudu meje, yaya meje, meje meje ni
Hallelujah meje at'abẹla meje fun ọjọ meje
[Chorus]
Malaika po ko ki
To ba ṣan ni ma ba ẹ ja
Malaika po ko ki
To ba ṣan ni ma ba ẹ ja
Ma ba ẹ
Po ko ki
To ba ṣan ni ma ba ẹ ja
Ma ba ẹ ja
Malaika po ko ki
Po ko ki
To ba ṣan ni ma ba ẹ ja
Ma ba ẹ
[Verse 1]
Puff puff pass no be taboo taboo
Mercedes benz no be kabukabu
Puff puff pass no be taboo
Don't know who is next up may be na you
Ẹni ba lo mọ
Ẹni mọ lo ba
Ẹni to mọ ko wa sọ
Ẹni mọ lo ba aye
[Verse 2]
Ṣe t'ọn gbe Chelsea mi
Emi ga-an gbe Hennessy wọn jọ
Wọn leku si mi
Emi gaan lẹran si wọn jọ
Ta ba n sunkun ka maa watch
Ka maa lo lence
O gbo o fẹ ra benz o wa lọ fo fence
[PreChorus]
No pain no gain
No name no fame, no face no case
Hallelujah meje at'abẹla meje fun ọjọ meje
Gudugudu meje, yaya meje, meje meje ni
Hallelujah meje at'abẹla meje fun ọjọ meje
[Bridge]
Po ko ki
Ma ba ẹ ja
[Chorus]
Malaika po ko ki
To ba ṣan ni ma ba ẹ ja
Malaika po ko ki
To ba ṣan ni ma ba ẹ ja
Ma ba ẹ
Po ko ki
To ba ṣan ni ma ba ẹ ja
Ma ba ẹ ja
Malaika po ko ki
Po ko ki
To ba ṣan ni ma ba ẹ ja
Ma ba ẹ
[Verse 3]
Ṣe t'ọn gbe Chelsea mi
Emi ga-an gbe Hennessy wọn jọ
Wọn leku si mi
Emi gaan lẹran si wọn jọ
Ta ba n sunkun ka maa watch
Ka maa lo lence
O gbo o fẹ ra benz o wa lọ fo fence
[PreChorus]
No pain no gain
No name no fame, no face no case
Hallelujah meje at'abẹla meje fun ọjọ meje
Gudugudu meje, yaya meje, meje meje ni
Hallelujah meje at'abẹla meje fun ọjọ meje
[Outro]
Ye I got money, I got money wa lọ mọ mi
Ọmọ jọ mummy, ẹlẹ daddy I got money eh
Written by: BhadBoi OML
instagramSharePathic_arrow_out