Lyrics

[Intro]
Uh uh uh uh
Eh eh eh eh eh
Ṣo le mujẹ?
[Chorus]
Mo ni pe t'ọn ba sọrọ kekere fun ẹ ṣo ma le mujẹ
Ọlọgbọn to n ṣe bi omugọ o ni bo ṣe jẹ
Ọrọ lasan la a sọ fun omugọ ti ko gbọn yẹn
A jọ maa lowo yii ni ko jẹ bo ba ṣe jẹ
To ba dẹ ti n ri bẹ ṣe fẹ ka ṣa maa dupẹ
Nnkan t'Ọlọrun mi ba fọwọ si e le bajẹ o
Adura to ju gan-an gan-an ni ki tiwa ma ṣe bajẹ o
Gbogbo ẹyin tẹ n fẹran mi tiwa o ni bajẹ, oh oh eh ye
[Verse 1]
If you no get money dem go take you play
Abi you think na one night work to get money like Dangote
You go tey oo, walahi you go tey ooo
Wa pẹ nibẹ
You go get brain when you don geti white bear bear
Emi o ni tanra mi o ma kuku ṣiṣẹ
Atẹlẹwọ ẹni ko ki n tanni jẹ
Emi o ni tanra mi o ma kuku ṣiṣẹ gbowo
Atẹlẹwọ ẹni ko ki n tanni jẹ
[Bridge]
Jẹjẹ jẹjẹ ṣa laye gba
Jẹjẹ lo le ṣe o
Jẹjẹ laye gba
Jẹjẹ yeh
Jẹjẹ jẹjẹ ṣa laye gba
Jẹjẹ lo le ṣe o
Jẹjẹ laye gba
Jẹjẹ
[Chorus]
Mo ni pe t'ọn ba sọrọ kekere fun ẹ ṣo ma le mujẹ
Ọlọgbọn to n ṣe bi omugọ o ni bo ṣe jẹ
Ọrọ lasan la a sọ fun omugọ ti ko gbọn yẹn
A jọ maa lowo yii ni ko jẹ bo ba ṣe jẹ
To ba dẹ ti n ri bẹ ṣe fẹ ka ṣa maa dupẹ
Nnkan t'Ọlọrun mi ba fọwọ si e le bajẹ o
Adura to ju gan-an gan-an ni ki tiwa ma ṣe bajẹ o
Gbogbo ẹyin tẹ n fẹran mi tiwa o ni bajẹ, oh oh eh ye
[Verse 2]
Emi o ni tanra mi o ma kuku ṣiṣẹ
Atẹlẹwọ ẹni ko ki n tanni jẹ
Emi o ni tanra mi o ma kuku ṣiṣẹ gbowo
Atẹlẹwọ ẹni ko ki n tanni jẹ
To ba dẹ ti n ri bẹ ṣe fẹ ka ṣa maa dupẹ
Nnkan t'Ọlọrun mi ba fọwọ si e le bajẹ o
Adura to ju gan-an gan-an ni ki tiwa ma ṣe bajẹ o
Gbogbo ẹyin tẹ n fẹran mi tiwa o ni bajẹ, oh oh eh ye
Written by: Barry Jhay, Oluwakayode Balogun
instagramSharePathic_arrow_out