Lyrics
[Intro]
Ori oh, ori lo gbe, yeah
Ẹlẹdaa ni mo pe, yeah
Jọwọ da mi lohun, ori oh
Nijọ tebi ba n pọna, nijọ tebi ba n pọna
K'emi ma ma rin lọna lọjọ naa oh, amin
[Verse 1]
Ori la ba bọ, a o ba fooṣa silẹ
Ori mi oh, ẹlẹdaa mi oh, eh-ahh
Ori la ba bọ, a o ba fooṣa silẹ
Ori mi oh, ẹlẹdaa mi oh
Ma sun lọ nigba kankan
Ori mi ma sun lọ, ori mi oh
Lọjọ t'Olugbala ba n pinre, jẹ o pe mi ohh, eh-ahh
Jẹ ki ire aye mi ko tẹ mi lọwọ
K'owo ma wọn mi nigba kankan
K'emi ma rowo na laye
Ori oh, ori lo gbe, yeah
Ẹlẹdaa ni mo pe, yeah
Jọwọ da mi lohun, ori oh
Nijọ tebi ba n pọna, nijọ tebi ba n pọna
K'emi ma ma rin lọna lọjọ naa oh, amin
[Chorus]
Ori la ba bọ, a o ba fooṣa silẹ
Ori mi oh, ẹlẹdaa mi oh, eh-ahh
Ori la ba bọ, a o ba fooṣa silẹ
Ori mi oh, ẹlẹdaa mi oh
Ma sun lọ nigba kankan
Ori mi ma sun lọ, ori mi oh
Lọjọ t'Olugbala ba n pinre, jẹ o pe mi ohh, eh-ahh
Jẹ ki ire aye mi ko tẹ mi lọwọ o
K'owo ma wọn mi nigba kankan
K'emi ma rowo na laye (Ori)
[Verse 2]
Ilẹkun aanu to ṣi lọjọsi, ohh
Ma jẹ ko ti mọ mi Baba
Ore to ṣe mi, to ṣe mi
Ko le ka lemi gbọdọ wọn mi Baba
Ibi ti maa de laye mi, ki n de'bẹ
Layọ, lai si wahala rara, yeah oh-ohh
Ibi ti ma de laye mi, ki n de'bẹ
Ba mi ṣe, ko dahun
Ba mi ṣe, jẹ ki n ṣeyọri ohh, ori oh
[Chorus]
Ori la ba bọ, a o ba fooṣa silẹ
Ori mi oh, ẹlẹdaa mi oh, eh-ahh
Ori la ba bọ, a o ba fooṣa silẹ
Ori mi oh, ẹlẹdaa mi oh
Ma sun lọ nigba kankan
Ori mi ma sun lọ, ori mi oh
Lọjọ t'Olugbala ba n pinre, jẹ o pe mi ohh, eh-ahh
Jẹ ki ire aye mi ko tẹ mi lọwọ o
K'owo ma wọn mi nigba kankan
K'emi ma rowo na laye (Ori)
[Outro]
Ori oh, ori lo gbe, yeah
Ẹlẹdaa ni mo pe, yeah
Jọwọ da mi lohun, ori oh
Nijọ tebi ba n pọna, nijọ tebi ba n pọna
K'emi ma ma rin lọna lọjọ naa oh, amin
Written by: Barry Wilfy Jhay