Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Tiphe
Performer
Niphkeys
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Tiphe
Songwriter
Niphkeys
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Niphkeys
Producer
Nuelgenie
Co-Producer
Oyedotun Emmanuel Oluwatobiloba
Co-Producer
Lyrics
[Verse 1]
Igi to ba mọmọ elewele sa nigbo
Awa dẹ ma tension wọn, wọn mọ tawa nijo
Kawa ṣa maa wo wọn niran ka maa carry go
Emi ọmọ ara-ma-sanwo, ki lẹ tun n duro wo?
[Chorus]
Eh, awa lagba, ki lo n ṣe awọn ṣẹṣẹde yii?
Awọn lo mọ ibajẹ wọn ko le stain mi
Awa lagba o, ki lo n ṣe awọn ṣẹṣẹde yii o?
Awa lagba, ki lo n ṣe awọn ṣẹṣẹde yii?
Nobody can chance emi dey maa carry go
Awa o dẹ le fọ fun wọn, wọn mọ tawa nijo
Kawa ṣa maa wo wọn niran ka maa carry go
Kawa ṣa maa wo wọn, kawa ṣa maa wo wọn
[Verse 2]
Make dem no go vex me, ma dabeẹ ru Tyson Fury
Emi a leṣan ba yin ja ko le rẹ mi ko le su mi
Cos sisi don go carry belle, pẹlẹ, you dey fly like Ben 10
Folorunsho don drive kẹkẹ with one leg dem no tell ham pẹlẹ
[Verse 3]
You go lesson o maa to gbọn
Dem no dey tell person o maa kọgbọn
You go learn lesson
Dem no dey tell person ahn, ahn
[Chorus]
Awa lagba, ki lo n ṣe awọn ṣẹṣẹde yii?
Awọn lo mọ ibajẹ wọn ko le stain mi
Awa lagba o, ki lo n ṣe awọn ṣẹṣẹde yii o?
Awa lagba, ki lo n ṣe awọn ṣẹṣẹde yii?
Nobody can chance emi dey maa carry go
Awa o dẹ le fọ fun wọn, wọn mọ tawa nijo
Kawa ṣa maa wo wọn niran ka maa carry go
Kawa ṣa maa wo wọn, kawa ṣa maa wo wọn
Kawa ṣa maa wo wọn, kawa ṣa maa wo wọn
[Outro]
Igi nla gbagbo ẹlẹyin bi oke
Igi nla gbagbo ẹlẹyin bi oke o
Igi nla gbagbo ẹlẹyin bi oke o
Written by: Niphkeys, Tiphe