Lyrics

[Intro]
Ye oooo
Hmm ye ooo
Hmm ye ooo
(It's Jayfred the beat wizard)
They call me fresh out ji ma sun, ji ma sun lele
Hmm ye ooo
Hmm ye ooo
[Verse 1]
Any ipo to ba wa ṣi ma dupẹ
Awọn kan sun lana wọn ji sẹ
Atimu naa ni atijẹ
Ọlọhun ma jẹ a rogun ibanujẹ
Baba ya wa si mimọ o
Eṣu lagbara ko ni igbala o
Ani lọla inu kan
Emi a gbera, ma jeniyan
[Verse 2]
Carry cross only me fit save me from me
Family gat me chasing money
I no fit make a promise
Make e no go turn is coming
Some are born rich dem get lucky
Wọn bi ibeji sinu trenches
Ehn, Oluwa lo n wo ọmọ
No go look down on anybody
[Chorus]
Ọla ni ka ro
Igbẹyin ma dun
Ani ma ṣe binu wọn
No go panic o
Ani, ọla ni ka ro
Igbẹyin ma dun
Ani ma ṣe binu wọn
No go panic o
[Verse 3]
Ọlọrun lo ranṣẹ pe anabi
Why anabi wan dey lobby
Ọjọ naa re bi ana bi
When some have food but cannot eat
Go, go, go, anywhere I go
Yago yago Bellingham o
And I go pago anyhow o
Oluwe
Wọn wa n pe were ni, were ni
Ọmọ to n tẹ wire lọsan-an
Wọn n pe were ni, were ni
Ọmọ to n fa wire loru
Wọn wa n pe were ni, were ni
Ọmọ to n lu chord lọsan-an
Wọn n pe were ni, were ni
A tun wa record loru
[Chorus]
Ọla ni ka ro
Igbẹyin ma dun
Ani ma ṣe binu wọn
No go panic o
Ani, ọla ni ka ro
Igbẹyin ma dun
Ani ma ṣe binu wọn
No go panic o
[Outro]
Wọn n pe were ni, were ni
Omo to n gba wire lọsan-an
Wọn n pe were ni, were ni
A tun wa record loru
(Who mix this?)
(Jesus)
Written by: Akinyinka Kuham Oladimeji, Kusimo Olawale Abeeb
instagramSharePathic_arrow_out