Lyrics
Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
Ọrọ mi d'akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn
Ẹni j'alangba n tutu, a ko warapa
Oh-ah, oh-ah-ah-ah
Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah
Oh-wa, oh, wa-wa-wa
(Nobody's perfect)
Yea, ki'ku ma-ma pa awọn to gbe mi s'ori bi gele
Ki ibaunjẹ jina siwa rere, ay, tefe-tefe
Ki'ku maa p'ọta mi, ko le riran-wo
(O ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah)
Ki'ku maa p'ọta mi, ko le riran-wo
(Mo ṣi n m'ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
If I see say wahala don dey too much
Na to roll up a big fat one, motivation gan-an ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o?
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
Yeah, as I dey find wetin I go chop, ooh-iy-iy
Make I no jam wetin go chop me
Oluwa lo gbe (yea-yea), lo gbe mi soke
Emi ko le ṣa i ṣọpẹ
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
Yeah, o loju ọmọ to damọ
If I see say wahala don dey too much
Na to roll up a big fat one, motivation gan-an ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
Yeah, o loju ọmọ to damọ
(Sunshine)
Writer(s): Oluwakayode Junior Balogun
Lyrics powered by www.musixmatch.com