Music Video

Diamond Jimma - Awuyewuye (Official Video)
Watch Diamond Jimma - Awuyewuye (Official Video) on YouTube

Featured In

Credits

COMPOSITION & LYRICS
Kusimo Olawale Abeeb
Kusimo Olawale Abeeb
Songwriter

Lyrics

[Verse 1]
Ikebe sọkutu wọ, wọ, wọ
O ṣe mi bi gan, gan, gan
Ko si iru ẹ ri Ọlọrun n gbọ
Ifẹ rẹ n da mi lọrun gan-an
Mo fẹ fi ẹ ṣaya mi lọrọ kan
Ojoojumọ lo n yọ bi ọjọ
Iwọ mo fẹ ma ri ọ lẹnikan
O n pa mi, o n pa mi, o ye, mo fọ
[PreChorus]
Whether you be Ibo or Hausa, Yoruba, e no matter
Can I know your name ọlọmọge? Ma ṣe gapa
I go pay you my cash
She say na lion mo ma pa
Ẹ gba mi, ẹ ra mi o, mo ti n foju comot wrapper
[Chorus]
Awuyewuye oh, awuyewuye
Awuyewuye oh, awuyewuye
Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga
Tẹ ba n wa mi kiri, mo ti gbale ẹ lọ
[Chorus]
Awuyewuye oh, awuyewuye
Awuyewuye oh, awuyewuye
Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga
Tẹ ba n wa mi kiri, mo ti gbale ẹ lọ
[Verse 2]
Woju mi
Wonu mi
Sọ fun mi
Ma joju mi
Ko ni su mi
Ẹyinju mi
Fara mọ mi
Ko sẹni to le fun mi
Ifẹ rẹ dun bi oloyin
Bi mo ri ẹ, o ti yo mi
Jọọ ma ṣe kanra mọ mi
[PreChorus]
Whether you be Ibo or Hausa, Yoruba, e no matter
Can I know your name ọlọmọge? Ma ṣe gapa
I go pay you my cash
She say na lion mo ma pa
Ẹ gba mi, ẹ ra mi o, mo ti n foju comot wrapper
[Chorus]
Awuyewuye oh, awuyewuye
Awuyewuye oh, awuyewuye
Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga
Tẹ ba n wa mi kiri, mo ti gbale ẹ lọ
[Chorus]
Awuyewuye oh, awuyewuye
Awuyewuye oh, awuyewuye
Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga
Tẹ ba n wa mi kiri, mo ti gbale ẹ lọ
[Outro]
Ahhh
Ah ah ah ah, mo de, woju mi
Ẹyinju mi
Ọmọ Abeokuta re wa oh
O ma gba dandan ni
E si un o ma ṣe
Written by: Daramola Oluwole, Kusimo Olawale Abeeb
instagramSharePathic_arrow_out