Lyrics

(No one is sleeker) Wọn ni ki n wa baba to sabi Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o Wọn ni ki n wa baba to sabi o (ehn-ehn, ehn) Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi (uhn-uhn, uhn) Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o Uh, ọmọ ologo to sabi Ọmọ gbera tan, o b'omi si garri O wọ Yankee o, Atlanta per roof Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun Uh, ọmọ ologo to sabi Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri O wọ Yankee o, Atlanta per roof Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun Huh, ki lo de o jere o? Mo ma j'aiye mi k'ọn to fun fere o Uh, o ṣe o, o ṣe, o ṣe o jere o Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma ko're oko de'le o Uh, wọn gun'yan mi kere o Mo fíìmu wọn fọn fere o Ninu aiye, mi o kere o To ba de igboro, ko lọ béère o Wọn ni ki n wa baba to sabi o Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o Wọn ni ki n wa baba to sabi o (ehn-ehn, ehn) Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi (uhn-uhn, uhn) Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o Uh, ọmọ ologo to sabi Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri O wọ Yankee o, Atlanta per roof Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun o Huh, ọmọ ologo to sabi Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri O wọ Yankee o, Atlanta per roof Èèyan Baba Fela ni, kẹ gba fun Huh, ki lo de o jere o? Mo ma j'aiye mi k'ọn to fun fere o Uh, o ṣe o, o ṣe, o ṣe o jere o Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma ko're oko de'le o Uh, wọn gun'yan mi kere o Mo fíìmu wọn fọn fere o Ninu aye, mi o kere To ba de igboro, ko lọ béèrè o I will exalt You, Lord For You have lifted me up Has not let my foes to rejoice over me (Timi Jay on the track)
Writer(s): Ayodele Ibukunoluwa, Promise Aloba Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out