Music Video

Naira Marley - Happy feat. Mayorkun [Audio]
Watch Naira Marley - Happy feat. Mayorkun [Audio] on YouTube

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Naira Marley
Naira Marley
Vocals
Mayorkun
Mayorkun
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Naira Marley
Naira Marley
Songwriter
Mayorkun
Mayorkun
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Rexxie
Rexxie
Producer

Lyrics

[Intro]
We are h-a-p-p-y (Believe you've gat another day)
We are h-a-p-p-y (No be madness, no be other)
We know we are
We are Marlians for life
We are h-a-p-p-y (Everyday issa holiday)
Happy geng geng
[Verse 1]
Mo fẹ confess, my dear (My dear)
MD ti burst, my dear (My dear)
Emi ti n sweat, my dear let's go, ka lo gba AC ninu Benz, my dear (Skrr, skrr)
I have gone far like Zinoleesky (Ehn-ehn)
I need Loud and fuckin' music (Hmm, mm)
I just have to gbọmọ meji
Because lalẹ yii, mo ni energy (Energy)
Emi o le sun bayii mọ oh (Bayii mọ oh)
Emi o le jẹun bayii mọ oh (Bayii mọ oh)
Emi o ni gbọja yii mọ oh
Psych, a ma tun gbe ki'lẹ to mọ, hi
What's all the talkin' about? (About)
What's all the gossip about? (About)
Talkin' my shit, you don't know shit about
Shibili, shabala, wo me, I'm high
[Chorus]
MD ti burst
Wọn ti n kọrin church
You know Mayor the rapper (Mayor turn rapper)
O tun n lo lamba (O tun n lo lamba)
MB ti cost
Wọn ti n kọrin church
You know Mayor the rapper (Mayor turn rapper)
O tun n lo lamba, ye, ye
[Verse 2]
Ọja eleyii jẹmi mi lọ oh, o ti burst (Burst)
Inu mi kan n dun latana ni oh mo gbe diẹ (Diẹ)
Igba to ṣe diẹ lo gbe mi lọ oh, Ọlọhun gba mi oh
Mo promise, mi o ni ṣe iru re mọ oh
O ma to gbe iwọ naa lọ (Lọ)
O lọ n ṣe bi alagbara ('ra)
Ọja o ma mọ ẹni kankan (Ọja o ma mọ ẹni kankan)
MD o ma mọ olowo (MD o ma mọ olowo)
Ọja to ṣẹyan mọlẹ (Ọja to ṣẹyan mọlẹ)
Eṣu to teṣu mọlẹ (Eṣu to teṣu mọlẹ)
O o lowo, o tun joko sile (Mi o joko sile)
O lowo o ṣana wọle (O lowo o ṣana wọle)
Ọmọ ase lago mọlẹ (Pa)
Ti tibi tibi wa nilẹ (Ahh)
Wọn fẹ ka salọ ni oh (Wọn fẹ ka salọ ni oh)
A dẹ ma dalẹ ni oh (A dẹ ma dalẹ ni oh)
To ba ti set, o ti set
O mo bo ṣe n lọ we already met (Met)
O n f'ẹmi ẹ play Russian Roulette (Roulette)
O n yọbẹ niwaju bullet (O n yọbẹ niwaju bullet)
[Verse 3]
Ṣo le gbe-gbe-gbe-gbe, k'oma burst?
Ko le gbe-gbe-gbe-gbe
To ba ti lowo lọwọ (Ko gbe)
O dẹ lori meji (Ko gbe)
O kuku koju sapo (Ko gbe)
Ko gbe (Gbe-gbe-gbe)
[Chorus]
MD ti burst
Wọn ti n kọrin church
You know Mayor the rapper (Mayor turn rapper)
O tun n lo lamba (O tun n lo lamba)
MB ti cost
Wọn ti n kọrin church
You know Mayor the rapper (Mayor turn rapper)
O tun n lo lamba
[Outro]
We are h-a-p-p-y (Believe you've gat another day)
We are h-a-p-p-y (No be madness, no be other)
We know we are
We are Marlians for life
We are h-a-p-p-y (Everyday issa holiday)
Written by: Mayorkun, Naira Marley
instagramSharePathic_arrow_out