Featured In

Lyrics

[Chorus]
Ọmọ Anifowoṣe
Ọmọ anifo
Iru ki leyi
Ọmọ Anifowoṣe
Ọmọ Anifo'
Iru ki leyi
Ọmọ Anifowoṣe
Wọn m'ewurẹ dudu
Wọn mu re'gbo Ifa
Ọmọ Anifowoṣe
Wọn m'aguntan bọlọjọ
Wọn mu re ile Ọṣun
Ọmọ Anifowoṣe
Ọṣun o gba aguntan
Ẹ ma ṣe gbẹmi mi
Ọmọ Anifowoṣe
Ẹni ti o ṣe bi alaaru l'Oyingbo
Ko le ṣe bi Adegbọrọ l'Ọja-Ọba
Ayinde ooh eh
Ayinde ooo
[Verse 1]
Wọn ni ki lo de?
Ki lo ba de, ki lo n wa n'bi, wọn ki lo fẹ?
They never thought I'll make it to the top
But that's not fair
To ri mommy wa o lowo
To ri daddy wa o lowo
Hustled from the house and praying every damn day, na sorrow
Mo ya jẹ solo o
A dẹ solo o
Dem be high class dem say we are so low o
[Verse 2]
Mommy taṣọ ati bata ẹ fun paarọ
Daddy taṣọ ati bata ẹ fun paarọ
To put food on the table
Ko ma dabi pe wọn wa capable
Salary daddy o wa stable
Everyday kọ la maa n jẹ vegetable
Buh mummy know God is able, ice water la ma tun fi mu gari lẹbu
Awọn ọmọ landlord, chance wa
Tori pass wa, wọn embarass wa
Wọn ni ẹ kuro ni house wa
Wọn frustrate mommy ati house wa
Mo sọ fun pe awọn ọmọ Alhaja
T'ọn ba so mi mọlẹ n ile yii, ma a ja
Ma a ja, mi wa ja but t'owo mi ba d'eeyan, wa a ja
[Chorus]
Ọmọ Anifowoṣe
Ọmọ anifo
Iru ki leyi
Ọmọ Anifowoṣe
Ọmọ Anifo'
Iru ki leyi
Ọmọ Anifowoṣe
Wọn m'ewurẹ dudu
Wọn mu re'gbo Ifa
Ọmọ Anifowoṣe
Wọn m'aguntan bọlọjọ
Wọn mu re ile Ọṣun
Ọmọ Anifowoṣe
Ọṣun o gba aguntan
Ẹ ma ṣe gbẹmi mi
Ọmọ Anifowoṣe
Ẹni ti o ṣe bi alaaru l'Oyingbo
Ko le ṣe bi Adegbọrọ l'Ọja-Ọba
Ayinde ooh eh
Ayinde ooo
[Verse 3]
Mo n da gbe, mo n da fa a
Mi o mọle oniṣegun, mi o mọle alfa
Bo ya mommy ati daddy lo ṣiṣẹ lori mi
Glory be to Alpha
Before, life hard
Poverty fi mi ṣe cypher
Sorrows and pain ma fi mi cat walk
Wọn ma tun ṣe high 5
So we roll up just to get high, but
Poverty no stop so my guys open eyes
Ọga Ade
Ẹ wo ibi ta ba de
Ọmọ ẹru d'ọba
Igboro de mi lade
Ẹ ma kun pancake
Me I am getting my cake
**** dem be like eh
When they see my picture on the like eh
Them no rich God
Them know this
Wọn fẹ ṣi office le mi lori
Ṣe mo jọ novice?
God, I love this
I keep rolling like a borris
Versace, Versace
You rocking Versace
Your mommy is suffering, oloṣi
Emi ti flourish, awọn parents mi n jẹun to nourish
[Chorus]
Ọmọ Anifowoṣe
Ọmọ anifo
Iru ki leyi
Ọmọ Anifowoṣe
Ọmọ Anifo'
Iru ki leyi
Ọmọ Anifowoṣe
Wọn m'ewurẹ dudu
Wọn mu re'gbo Ifa
Ọmọ Anifowoṣe
Wọn m'aguntan bọlọjọ
Wọn mu re ile Ọṣun
Ọmọ Anifowoṣe
Ọṣun o gba aguntan
Ẹ ma ṣe gbẹmi mi
Ọmọ Anifowoṣe
Ẹni ti o ṣe bi alaaru l'Oyingbo
Ko le ṣe bi Adegbọrọ l'Ọja-Ọba
Ayinde ooh eh
Ayinde ooo
[Outro]
Long live King Wasiu Ayinde Marshall
Thanks for the inspiration, Papi
Living legend to bad
Kwam1, the Ultimate
Mo sample your voice, baba, ẹ ma kana
Olamide Badoo
Written by: Olamide Adedeji
instagramSharePathic_arrow_out