Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Ayo Maff
Ayo Maff
Lead Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Abatan Enioluwa Olumide
Abatan Enioluwa Olumide
Songwriter
Adisa Oluwatomi King
Adisa Oluwatomi King
Songwriter
AYORINDE AYODELE MAFOLUKU
AYORINDE AYODELE MAFOLUKU
Songwriter
Juju the Pen
Juju the Pen
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
PS10
PS10
Producer

Lyrics

[Intro]
Ayo! Ayo Maff!
[Verse 1]
Ọna lo jin
Ọna lo jin, ẹru ni baba
Ọmọ oro mi
Ọmọ oro mi, client ma sanwo
Igba ta ba le tẹramọ hustle yii
Say wọn ma sanwo
Ọmọ oro mi, ọmọ oro mi
No give up my padi
[Verse 2]
Duro ti mi Shade
Duro ti mi shade
Duro ti mi lalẹ yii
Ha duro ti mi Shade o
Omije loju mi my padi
I go school mi o le pari
And no be say I no sabi
But owo lo mi ṣojoro
Mumsy mi o le sọrọ mọ
My popsy no fit para
Ọmọ boy ti n fa poli
Ọmọ boy ti n mu gbo o
[Chorus]
Tori ko sowo ni ile
Eh ehhhhh eh eh eh eh
Ko sowo ni ile eh eh eh (Owo nile o)
Tori ko sowo ni ile
Eh ehhhhh eh eh eh eh
Ko sowo ni ile eh eh eh (Owo nile o)
[Verse 3]
Jama, jama, jama
Cause ole lo bọmọ jẹ
Gbowo ka fa cana
Ase o le jo Micheal Jackson
Jama, jama, jama
Ọmọ oro ma kana finishing
Jama, jama, jama
Ole lo bọmọ jẹ ẹ
[Verse 4]
Ah igboro o rẹrin-in
Aye o fẹni fọrọ
Ko n ṣe ibi la ma ku si
Ko n ṣe ibi lama kusi
So I tie my worries for backwood
I smoke the pain away
Iyo iyo iyo iyo iyo
[Chorus]
Tori ko so owo ni ile
Eh ehhhhh eh eh eh eh
Kosi owo ni ile eh eh eh (Owo nile o)
Tori ko so owo ni ile
Eh ehhhhh eh eh eh eh
Kosi owo ni ile eh eh eh (Owo nile o)
[Verse 5]
Ha, wọn fọmọ ẹru yẹn ṣere
Ọmọ ẹru le rale
Ọmọ ẹru le ra mọto o
Tọmọ ẹru ba gba lotto o
Ọmọ ẹru le d'ade
Ọmọ ẹru le jade
Tọmọ ẹru ba jade tan
Tori wọn pe mi lọmọ ẹru
I control my emotions
Kọrin bi Frank Ocean
You no fit take my portion
[Verse 6]
Ọna lo jin
Ọna lo jin oh
Towo mi ba de ma ra Gucci
Towo mi ba de ma ra Gucci o
My brother dey for Gwagalada
Ta ba rira jẹ ka fa Canada
[Outro]
To ba de
Towo mi ba de eh
To wo yi ba de o
Koba!!!
Written by: AYORINDE AYODELE MAFOLUKU, Abatan Enioluwa Olumide, Adisa Oluwatomi King, Juju the Pen, Oluwamayowa Olumide Oyefeso
instagramSharePathic_arrow_out