Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Rybeena
Rybeena
Vocals
Samad Abiola Salaudeen
Samad Abiola Salaudeen
Performer
Jboysings
Jboysings
Background Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Ayopelumi Israel Olatunji
Ayopelumi Israel Olatunji
Songwriter
Samad Abiola Salaudeen
Samad Abiola Salaudeen
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Haystixx
Haystixx
Producer

Lyrics

[Verse 1]
Now I'm fucked up in my head
Tinuke wants to be my babe
Amaka wants to be mine
O ti wa da nbi ta ba de
Shalewa carry me go vaca'
My mama wants Halimah
Me I no go lie ọmọ me I like ṣina
Get girls from Lagos, wọn wa l'IB naa
Wọn ni pe mo hands', wo bi skin yẹn ṣe n dan
I don’t kiss and tell only you and I will know
[Chorus]
Oh Shade
You know I get babe, ani ko kan aye
Mo lọmọ n Togo, ọmọ to gbọ Faranse
Sugar mummy to ma n tẹwo lati Kumasi (Kumasi o)
[Chorus]
Oh Shade
You know I get babe, ani ko kan aye
Mo lọmọ n Togo, ọmọ to gbọ Faranse
Sugar mummy to ma n tẹwo lati Kumasi, Kumasi o
[Verse 2]
Brown skin girl, o jọ Victoria Khimani
You gat me girl, iwọ lo jẹ ki ẹnu ka mi
Anybody fuck with you, girl I won't take it lightly (I won't take it lightly)
Ṣo ma lo mọ agba singing, ọkọ omidan?
Laarin 1,2,3 seconds ni mo fi fọ
She say I get sweet mouth daddy mi ni mo fi jọ
[Verse 3]
Ṣebi jẹjẹ mi ni aparte
L'emi ati awọn **** mi fi casami ṣaye
As soon as she enter me no fit look away
I no know when my igbo fall
I’m loosing focus
So many chikala want to knack me
But I pray dem never catch me lacking
Ẹlẹyinju mi iyẹn ni bakassi
Na only she support when I’m in a crisis
[Bridge]
To ju ba yẹju kohun, kohun, kohun ma ṣe yẹ
Kohun, kohun, kohun ma ṣe yẹ
Ti n ba ṣọmọ lọ mo ṣọmọ bọ, you'd still be my baby girl
You’d still be my baby girl
[Bridge]
To ju ba yẹju kohun, kohun, kohun ma ṣe yẹ
Kohun, kohun, kohun ma ṣe yẹ
Ti n ba ṣọmọ lọ mo ṣọmọ bọ, you'd still be my baby girl
You’d still be my baby girl
[Verse 4]
Chimamanda Hilda Baci
Sumaiya, ọmọ Fulani wa nasty
Arike ade iyẹn ni bakassi
Deborah she support when I’m in a crisis
Ẹ gba mi o
Albino lọmọ, mo ni jojo
Ọmọ ti o fẹ wahala, ko ni iṣoro
Benita crash lọdọ mi Sosolisoso
I no even save her contact for mi phone o
Ye, for mi phone o
[Chorus]
Oh Shade
You know I get babe, ani ko kan aye
Mo lọmọ n Togo, ọmọ to gbọ Faranse
Sugar mummy to ma n tẹwo lati Kumasi (Kumasi o)
[Chorus]
Oh Shade
You know I get babe, ani ko kan aye
Mo lọmọ n Togo, ọmọ to gbọ Faranse
Sugar mummy to ma n tẹwo lati Kumasi, Kumasi o
[Refrain]
To ju ba yẹju kohun, kohun, kohun ma ṣe yẹ
Kohun, kohun, kohun ma ṣe yẹ
Ti n ba ṣọmọ lọ mo ṣọmọ bọ, you'd still be my baby girl
You’d still be my baby girl
[Refrain]
To ju ba yẹju kohun, kohun, kohun ma ṣe yẹ
Kohun, kohun, kohun ma ṣe yẹ
Ti n ba ṣọmọ lọ mo ṣọmọ bọ, you'd still be my baby girl
You’d still be my baby girl
Written by: Ayopelumi Israel Olatunji, Samad Abiola Salaudeen
instagramSharePathic_arrow_out