Lyrics

[Verse 1]
Taba sunkun ka ma riran
Ọrọ pọ ninu iwe kobo
Igba wo la ma sọ gan-an
oh ahh
Ma finu wenu ko ma jẹwọ
If you act so dumb o le jẹlọ
Play me your cassette jẹ n gbọ
For this life, nobody love you pass mama, she no fit wish make you fall
For this side, what doesn't kill you make you stronger, now we build like a thug
Shoe get size
Some people go build mansion while some people go dey ṣọ
Alhamdulilah where I dey yesterday no be where I go dey tomorrow
[Chorus]
Ara mo n da
Ara mo n da
Kẹni ẹlẹni ma gbaṣe mi, ara mo n da
Ara mo n da
Ara mo n da
Kẹni ẹlẹni ma gbaṣe mi, ara mo n da
[Verse 2]
Iwa lọba awure
So mo kawọ mi soke
Mo kunlẹ mo gbadura, sohun gbogbo mo dawọle
Mi o ran ẹ, opeke
Why to wa lọ n lẹ OPay?
Ṣe na me dey knack you? Gbẹnu lọ mi o ba ẹ argue
Wọn dẹ ti mọwa nigboro
Garri wa o need ipolowo
Ko to di woro si woro
As ọmọ ọgbọn mo ti gbera nigboro
Oju to ma la a ri o
Ẹ ṣa a le de fila si idodo
Ẹni ba pori mi nibi ko ṣa ti mọ po ma rinlọ ni hoho
[Chorus]
Ara mo n da
Ara mo n da
Kẹni ẹlẹni ma gbaṣe mi, ara mo n da
Ara mo n da
Ara mo n da
Kẹni ẹlẹni ma gbaṣe mi, ara mo n da
[Verse 3]
Iwa lọba awure
So mo kawọ mi soke
Mo kunlẹ mo gbadura, sohun gbogbo mo dawọle
Mi o ran ẹ, opeke
Why to wa lọ n lẹ OPay?
Ṣe na me dey knack you? Gbẹnu lọ mi o ba ẹ argue
Written by: OLUWATIMILEHIN ADEMOLA SAMUEL
instagramSharePathic_arrow_out