Featured In
Top Songs By Balloranking
Credits
PERFORMING ARTISTS
Balloranking
Vocals
L.A.X
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Balloranking
Songwriter
L.A.X
Songwriter
Lyrics
[Intro]
N′Orile, orin ti de
Ojuelegba, wọn ma ṣa ẹ lẹgba
Ni Surulere, wọn o ni suru (Ooh-ooh, ohh)
Yeah-yeah, you know say na Zero Pa'
I am Balloranking
(Sh'-Sh′-Shakablaka)
[PreChorus]
Ọmọ, mo ya gbọna ti mi mọ (Ti mi mọ)
If sapa dey, I mọ pe o ni ba mi lọ (O ni ba mi lọ)
Name any hustler, dey for Babylon (For Babylon)
If I no make am, ta lo fẹ ba mi gbọ? (Fẹ ba mi gbọ?)
Mm, ṣo ma jẹ ki n mọ bo dẹ ṣe ma jẹ? (Ṣe ma jẹ?)
Mo ni ṣo ma pade mi to ba ti dalẹ? (′ba ti dalẹ?)
Ṣebi awọn paddie mi ni "ko ma lọ bẹ" (Ko ma lọ bẹ)
Jọ, ṣo ma wa pẹlu mi, ba mi kalẹ? (Ba mi kalẹ)
[Chorus]
Iyi atọla ni mo wa lọ, ah (Wa lọ)
Mo ti rire, mo rayọ (Rayọ)
Gbẹdu gbe de, Kuramo (′Ramo)
Na lie, t'ọn ba l′awọn o damọ (Damọ)
Ki lo fẹ fa karamọ? (Karamọ)
Wọn l'awọn o mọ-ọnmọ (O mọ-ọnmọ)
Wọn jọla Muhammād
O ya give dem, jẹ ki wọn ma sọhun t'ọn sọ, ay, ah, ah
[Verse 1]
Baby, don′t leave me now
Dakun, ma da mi, jọ
You know me sharp shooter, I'll give you proper now
Sweetie love, my dear oh
You know say me no there oh
Iwọ lo le gbe mi de'bẹ oh
Pretty love, my dear-eh
[Verse 2]
Girl, you be my super charger oh
Say if dem try, ọmọ, na back to sender oh
Mmm, baby, make we meet for zanga oh
You know say me and Ballo′ give them bangers (Mmm)
Ọmọ, baby, ma jẹ ka ja
I go dey give am to you faster-faster
Baby-baby, ma jẹ ka ja oh
I go dey give am to you faster-faster oh
So, make we link up, link up, link up
Shayo, drink up, drink up, drink up
[PreChorus]
Ọmọ, mo ya gbọna ti mi mọ (Ti mi mọ)
If sapa dey, I mọ pe o ni ba mi lọ (O ni ba mi lọ)
Name any hustler, dey for Babylon (For Babylon)
If I no make am, ta lo fẹ ba mi gbọ? (Fẹ ba mi gbọ?)
Mm, ṣo ma jẹ ki n mọ bo dẹ ṣe ma jẹ? (Ṣe ma jẹ?)
Mo ni ṣo ma pade mi to ba ti dalẹ? (′ba ti dalẹ?)
Ṣebi awọn paddie mi ni "ko ma lọ bẹ" (Ko ma lọ bẹ)
Jọ, ṣo ma wa pẹlu mi, ba mi kalẹ? (Ba mi kalẹ)
[Chorus]
Iyi atọla ni mo wa lọ, ah (Wa lọ)
Mo ti rire, mo rayọ (Rayọ)
Gbẹdu gbe de, Kuramo (′Ramo)
Na lie, t'ọn ba l′awọn o damọ (Damọ)
Ki lo fẹ fa karamọ? (Karamọ)
Wọn l'awọn o mọ-ọnmọ (O mọ-ọnmọ)
Wọn jọla Muhammād
O ya give dem, jẹ ki wọn ma sọhun t'ọn sọ, ay, ah, ah
[Bridge]
Burst my speaker, gimme your knicker
All on me dancer, or in my nice car?
Gimme your knicker, whines 'pon ni star
Only me, dies-ah, bicyclely style
Gimme distance, don′t let me distant
All of my guys are, pornstar, my ****
[Outro]
Mo ti rire, mo rayọ
Mm-mmm, ọla ni mo wa lọ
Mo ti rire, mo rayọ
Mo rayọ, yeah-yeah
A onile, to salọ
Aroye ko kagbọn
A onile, to
Written by: Balloranking, L.A.X