Lyrics

[Verse 1]
Shock wọn bakan o, Ọlọrun
Jiji mo ji lowurọ yii o
As e dey go make I find my own
Make you no use your own spoil my own
Mi o lazy mo n duro d'ogo
Jiji mo ji lowurọ yii o
Ohun ti maa jẹ ni mo n wa o eh
Na why I dey hustle like everyday
Kọmọ ọlọpẹ ma lọ ṣanpa lọle
[Chorus]
Ba ṣe n gbadura
Adura maa gba
Adura ti gba
A dẹ ma rowo pe ranṣẹ
Ba ṣe n gbadura
Adura ti gba
Adura ti gba
A dẹ ti rowo pe ranṣẹ
[Verse 2]
Tori ghetto mo ti wa o
Bi mo ṣe n bọ mi o kowo wa o
Money no dey pocket na why I dey change my budget o
Baba gbọ adura wa
Tori ko si ẹda to mọla
Wọn ni lagbaja no get money
Na why e dey cover face like this
Calamity
How money go be identity
Poor go call am vanity
Owo pọ lapo
Bi ti El Chapo
Pablo ọmọ Escobar
Ka maa rowo lo
Ka maa rowo na
Owo pọ lapo
Biti El Chapo
Pablo ọmọ Escobar
Ka maa rowo na
[Chorus]
Ba ṣe n gbadura
Adura maa gba
Adura ti gba
A dẹ ma rowo pe ranṣẹ
Ba ṣe n gbadura
Adura ti gba
Adura ti gba
A dẹ ti rowo pe ranṣẹ
[Outro]
Awa ọmọ rẹ a wa bẹbẹ
Awa ọmọ rẹ a wa bẹbẹ
Awa ọmọ rẹ a wa bẹbẹ
Written by: Fakoya Qudus, Oloruntimilehin Timothy Olorunyomi
instagramSharePathic_arrow_out