Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Qdot
Qdot
Performer
Harry Aye
Harry Aye
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Fakoya Qudus
Fakoya Qudus
Songwriter
Harry
Harry
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
SaucyMadeIt
SaucyMadeIt
Producer
Xsmile
Xsmile
Mixing Engineer

Lyrics

[Intro]
Ẹ ba n ki abiamọ
Iya ni iya to bi mi lọmọ o
Ọmọ ọmọ Moriamọ
[Chorus]
Iya mi gbọdọ jẹun ọmọ
Tori o jiya lori mi
Nigba yẹn ko ma sẹni to ri mi
Mi o ni sunkun rẹ, o ni foju sunkun mi
Iya mi lo mọ bi mo ṣe dagba
O ma dogbo o ma dagba
Ẹ ba n ki mother mi
Ati inu oyun lo ti n ṣe teacher mi
[Verse 1]
Thank you for my mother that you give me life
Ọlọhun lo mọ batọ ṣe dọmọ
Bọ'n fẹ bọ'n kọ o ma jẹun ọmọ
Tori ọwọ oriṣa ko lo ti tọrọ ọmọ
Nobody know how water enter coconut
Baba mi loke jẹ n rowo na
Ọmọ tapatadide ninu ẹrẹfọ
If I no do for my blood who I go do for
Everything I get I de pray for
Ọmọ ologo ni mi I no fit fall
I pray
I pray
I pray, I pray, I Pray
Ẹ ba n ki (Abiyamọ)
Abiyamọ, abiyamọ, ku ọrọ ọmọ
Abiyamọ abiyamọ, ku ọrọ ọmọ
[Chorus]
Iya mi gbọdọ jẹun ọmọ
Tori o jiya lori mi
Nigba yẹn ko ma sẹni to ri mi
Mi o ni sunkun rẹ, o ni foju sunkun mi (I pray)
Iya mi lo mọ bi mo ṣe dagba
O ma dogbo o ma dagba (O ma darugbo)
Ẹ ba n ki mother mi
Ati inu oyun lo ti n ṣe teacher mi
[Verse 2]
Ah ahh ahhn
Nobody nobody know
Ọmọ ologo ni mi, mi le ṣẹnusọ
What I have seen nobody else have seen
Feel it in my heart man I feel it in my soul
Yeah mo dupẹ lọwọ Ọlọhun
Ọmọ story mi can't be televised
Everytime I think I'm only realising
My intuition can be patronising
Staring at the ceiling looking for a vision
I'm just another man that is on a mission
Mama mi lo sanwo nigba admission
Obinrin kan bi ọkunrin mẹta
Wọn carry mi, idunnu wọn fi bi mi
Simileoluwa, Harryportman Adetokunbo
Wọn ni o ku diẹ wọn ba bi mi si London
Only Baba God know the reason for
Oluwa ba mi ṣe ko ki i jẹ ki n ranti
Ireti mi wọn ti ran si mi
Emi lọ Adekunle Gold lọmọ
O lọ, o bọ, kini ki wọn sọ?
Wọn ro wi pe mi ni ṣe rere
Awọn to ba ni ki wọn maa jona lọ
[Chorus]
Iya mi gbọdọ jẹun ọmọ
Tori o jiya lori mi
Nigba yẹn ko ma sẹni to ri mi
Mi o ni sunkun rẹ, o ni foju sunkun mi (I pray)
Iya mi lo mọ bi mo ṣe dagba
O ma dogbo o ma dagba (O ma darugbo)
Ẹ ba n ki mother mi
Ati inu oyun lo ti n ṣe teacher mi
Ati inu oyun lotin se teacher mi
Written by: Fakoya Qudus, Harry
instagramSharePathic_arrow_out