Music Video

Qdot - Alhamdulillah (Thank God) (Official Video)
Watch Qdot - Alhamdulillah (Thank God) (Official Video) on YouTube

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Qdot
Qdot
Performer
PRODUCTION & ENGINEERING
2TBoyz
2TBoyz
Producer

Lyrics

[Verse 1]
Awọn alfa wa n'Ilorin (N'Ilorin, n'Ilorin)
Ti wọn kọ wa ni kehu (Ni kehu, ni kehu)
Ọrẹ Ọlọhun ni wọn ṣe (Ni wọn ṣe, ni wọn ṣe)
Ọrẹ Ọlọhun ododo
[Verse 2]
Tori won o gbemi dugbẹ (Alhamdulillah)
Mo riọdun to kọja (Alhamdulillah)
Mo tun rọdun yii (Alhamdulillah)
Ọdun yii ma dun-dun, dun (Alhamdulillah)
Owo o tan lara mi (Alhamdulillah)
Hennessy n lọ lẹnu mi (Alhamdulillah)
Colorado o gbe mi d'Aro (Alhamdulillah)
Ọmọ araye o ba mi daro (Alhamdulillah)
Ṣebi Iwọ lo wa lẹyin mi (Alhamdulillah)
Iwọ lo n dun lẹyin mi (Alhamdulillah)
O n dun ramu ramu (Alhamdulillah)
O n dun gbamu gbamu (Alhamdulillah)
Iwọ lo jẹ n ṣe e lasan (Alhamdulillah)
Iwọ lo jẹ ki n ṣaisan (Alhamdulillah)
O jẹwọ agbara rẹ (Alhamdulillah)
O jẹ k'aye fi mi ṣẹsin (Alhamdulillah)
[Chorus]
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
[Verse 3]
Mo dupẹ Ọlọhun (Alhamdulillah)
Ọpẹ ni pe Iwọ l'Ọlọhun (Alhamdulillah)
Emi l'ọmọ at'apatadide (Alhamdulillah)
Mo mọ ile ti mo ti jade (Alhamdulillah)
Mo dupẹ Ọlọhun, mo bẹbẹ (Alhamdulillah)
Iwọ lo mọ bi mo ṣe bẹrẹ (Alhamdulillah)
Sportybet fẹ gbaṣọ lọrun mi (Alhamdulillah)
Ọpẹ lọrọ l mi (Alhamdulillah)
Ti o ba ṣe po da sọrọ mi (Alhamdulillah)
Ibi ori dani si (Alhamdulillah)
Kọ lọkada ja mi si (Alhamdulillah)
L'ọpẹlọpẹ Messi (Alhamdulillah)
Ah, tani Mbappe? (Alhamdulillah)
Tori baba mi o lowo (Alhamdulillah)
O da iya mi lolowo (Alhamdulillah)
Talaka wa o taraka (Alhamdulillah)
[Chorus]
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
Alhamdulillah (Alhamdulillah)
[Outro]
M io fa jombo, mi o fa tiny mo (Alhamdulillah)
Mi o fa cigar, mi o fa wahala mo (Alhamdulillah)
Ṣina mi o pọju, ọti mi o pọju mọ (Alhamdulillah)
Emi o ba wọn f'igbo ṣinu mọ (Alhamdulillah)
instagramSharePathic_arrow_out