Lyrics

A'udhu bi kalimaat-illaahit-taammah Min kulli shaytaanin, wa haammah wa min kulli 'aynin laammah A'udhu bi kalimaat-illaahit-taammah Min kulli shaytaanin, wa haammah wa min kulli 'aynin laammah Oba ma je n soonu o Oba ma je n soonu o Oba ma je n soonu o Iji aye, aye yii po o Imole da wami ri Imole da o Imole da o Iji aye, aye yi po o Oluwa da abo bo mi Da abo bo mi Ma je n rinu o Ma je n rinu o Iji aye, aye yii po o Adele ba ire Arina ko ire Akoya ibi Je n mu're dele Adele ba ire Arina ko ire Imole da wami ri Imole da o Imole da o O ba mo je n soonu o Nítorí wón de àwòn sílè fún mi láinídi. Wón si gbé kötò sílè dè mí láinídií Jé kí iparun dé bá won lójiji Jé kí àwòn tí wón de sílè dè mí mú won Jé kí wón kó sinu rè, kí wón si parun! Nígbà náà ni n óo máa yò ninu OLUWA N óo sì yo ayò lá nítorí igbalà rè. N óo fi gbogbo ara wí pé, OLUWA, ta ni ó dàbí re? lwo ni ò n gba aláîlágbára lówó eni tí ó lágbára Tí o sì n gba aláilágbára ati aláiní Lówó eni tí ó fé fi wón se ìje Oluwa saanu funmi Mo bèèbèè Imole da wami ri Imole da o Imole da o Okunkun aye, aye yi suu o Imole o Imole o Imole A'udhu bi kalimaat-illaahit-taammah Min kulli shaytaanin, wa haammah wa min kulli 'aynin laammah A'udhu bi kalimaat-illaahit-taammah Min kulli shaytaanin, wa haammah wa min kulli 'aynin laammah
Writer(s): Teledalase Ogundipe Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out