Top Songs By Beautiful Nubia
Similar Songs
Credits
COMPOSITION & LYRICS
Segun Akinlolu
Songwriter
Lyrics
[PreChorus]
Ojumọ ti mọ, ara mi ẹ gbe'ra n'ilẹ, iṣẹ ti ya
Ojumọ ti mọ, ọrẹ mi ẹ gbọn'ra jigi ka tun'ra mu
Oniṣẹ ọwọ, alakọwe, gbogbo ẹni to n waṣẹ, ọmọ'lewe o
[Chorus]
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Wọn a ṣe'ba owurọ o

Waa ṣe'ba owurọ o, let go my beautiful sisters
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Wọn a ṣe'ba owurọ o
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Waa ṣe'ba owurọ o

Jẹ a ṣe'ba owurọ o, let's go once again
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Wọn a ṣe'ba owurọ o
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Waa ṣe'ba owurọ o
[Verse 1]
Good morning I greet you
How do you do?
Good morning I greet you
We've got some work to do
Good morning I greet you
How was your night?
Good morning I greet you
It will be a beautiful day
If you do your work
With honesty and pride
You will find your dreams coming true very soon
Said, "If we could be patient"
And live within the law
There will be much progress everyone will be happy
[Verse 2]
Good morning I greet you
How do you do?
Good morning I greet you
We've got some work to do
Good morning I greet you
How was your night?
Good morning I greet you
It will be a beautiful day
[PreChorus]
Ojumọ ti mọ, ara mi ẹ gbe'ra n'ilẹ, iṣẹ ti ya
Ojumọ ti mọ, ọrẹ mi ẹ gbọn'ra jigi ka tun'ra mu
Oniṣẹ ọwọ, alakọwe, gbogbo ẹni to n waṣẹ, ọmọ'lewe o
[Chorus]
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Wọn a ṣe'ba owurọ o
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Ẹ ma jẹ a ṣe'ba owurọ o, let's go beautiful people
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Wọn a ṣe'ba owurọ o
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Waa ṣe'ba owurọ o
One more time
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Wọn a ṣe'ba owurọ o
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Waa ṣe'ba owurọ o, ah
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Wọn a ṣe'ba owurọ o
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Waa ṣe'ba owurọ o
Let's go again
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma r'ire o, ẹni ma r'ire o
Wọn a ṣe'ba owurọ o
Owurọ l'ọjọ, ẹni ma
Written by: Segun Akinlolu