Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Teledalase
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Teledalase Ayomide Ogundipe
Songwriter
Lyrics
[Verse 1]
Mo nifẹẹ rẹ ni tootọ
N o purọ
N o purọ o
Mo mọ ọgbẹ ọkan rẹ ni tootọ
Amọ emi yatọ o
N o purọ
N o gbe ọ rindo, ẹsẹ rẹ o ni kanmi
N o ba ọ roke, ẹsẹ rẹ o ni kanlẹ
Mo ṣọgbingbin jẹ n ba ọ lọ
Ibi o ba n lọ, n o ba ọ re, n o ba ọ re
Ayanfẹ, jẹ n ba ọ rele o
Ibi o ba n lọ, n o ba ọ lọ, n o ba ọ lọ
[Verse 2]
Wọn ni ki layanmọ mi? Mo ni iwọ ni
Wọn ni ki layanmọ mi? Ifẹ rẹ ni
Irin wa ti dajọrin, ẹbọ wa ti dajọgbe
N o purọ o
N o purọ o
N o gbe ọ rindo, ẹsẹ rẹ o ni kanmi
N o ba ọ roke, ẹsẹ rẹ o ni kanlẹ
[Chorus]
Ayanfẹ jẹ n ba ọ dele
Ibi o ba n lọ, ibi o ba n lọ
Ayanfẹ jẹ n ba ọ dele
Ibi o ba n lọ o, n o ba ọ lọ o
[Verse 3]
Ila lo mọ oriki ila o
Ogiri lo mọ oriki ọbẹ o
Ayanfẹ dakun dabọ ṣe temi
Ibi o ba n lọ o
[Chorus]
Ayanfẹ, Ayanfẹ mi
Ayanfẹ jẹ n ba ọ dele o
IIbi o ba n lọ, ibi o ba n lọ o
[Verse 4]
Ayanfẹ dakun ṣe temi
Irin wa ajọrin
Ẹbọ wa ajọgbe
Iku wa ajọku
Written by: Teledalase Ayomide Ogundipe