Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
MohBad
Lead Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Aloba Promise Oladimeji
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Austin Sinister
Producer
VERB. AJE
Mixing Engineer
Lyrics
[Intro]
Hustle d'ọdọ Naira
Imọlẹ
[Chorus]
Ah, emi ti mi o holy
Ọmọ pastor to n fa poli
Ti iya ti jẹ mummy
Mo tatan s'ori titi
Wa, ẹ ma da mi lẹbi o
Ọrọ aje mo n ba kiri o
Aboki kọ mi wire
Tools wa n'lẹ sẹ, mo ti ra plier, easy
[Verse 1]
Hustle d'ọdọ Naira
Mi o sun, ki n le gba dollar
Wọn lo o ri show fun mi ni Italy
Fun mi n milli, send owo si mummy and daddy
Gbagbo lọwọ Diara
Pe Micee ko ṣe transfer
Ma p'osho ti n ba horny
Fun deepthroat mi o ni iyawo I'm sorry
[Chorus]
Ah, emi ti mi o holy
Ọmọ pastor to n fa poli
Ti iya ti jẹ mummy
Mo tatan s'ori titi
Wa, ẹ ma da mi lẹbi o
Ọrọ aje mo n ba kiri o
Aboki kọ mi wire
Tools wa n'lẹ sẹ, mo ti ra plier, easy
[Verse 2]
Ori mi calcu'
Ori mi calculate
Mo meditate million inu account ki n to pe 28
Ẹlẹda mi ma sun
Bless me, mo ti hustle
Oju mi yọ mi o
O yọ mi o, brightness lappy fọ mi loju
[Verse 3]
Ọta sa tira
E mi n dẹ gbadura
Ọlọhun dẹ n dabira
Mi o wa ile-aye maya
What you singing fam'?
Owo mi o pe
O ma di gobe
Ma pe Sammy Larry wa
[Chorus]
Ah,e mi ti mi o holy
(E mi ti mi o holy)
Ọmọ pastor to fa poli
(Ọmọ pastor to fa poli)
Ti iya ti jẹ mummy
(Ti iya ti jẹ mummy)
Mo tatan s'ori titi
(Mo tatan s'ori titi)
Wa, ẹ ma da mi lẹbi o
(Ẹ ma da mi lẹbi)
Ọrọ aje mo n ba kiri
(Ọrọ aje mo n ba kiri)
Aboki kọ mi wire (Wire, wire)
Tools wa n lẹ sẹ, mo ti ra plier, easy (Mo ti ra plier)
[Outro]
Aje on the mix
Written by: Aloba Promise Oladimeji