Lyrics

[Intro]
Gbolar Mighty lele le hm hmm
As we no wish them bad nothing can stop our progress
Oh yeh eh yeh eh eh eh, Kogbagidi n gbe mi lọ
[Verse 1]
Me I no dey sleep on it
Every midnight mo fi n w'owo mi
Ye Baba fere si iṣe mi
Ma jẹ n ṣe lasan ki maye sanwo mi
Emi ni mo ṣiṣẹ mi
K'ẹni ẹlẹni ma jẹsẹ mi
Cause eh if I no get money
Waiting be my gain ninu aye yii?
[Chorus]
Isalẹ-Eko wọn o ṣere
Adeniji, Eko akete
Lagos Island wọn ma ṣa ẹ lẹgba
Ọmọ Mainland, awọn ọmọ ọlọba
Ninu Mushin wọn o gbọ paa
Lekki boiz wọn maa n tẹwo si aza
Inu Alaba n'ọn ti maa n naja
Owo lemi n wa emi o waja
[Verse 2]
Ṣe na like this we go dey rough am?
Man get vibe man no get raba
All my famzs tell me make I calm
Na agaod dey run am my brother
Oju ẹni ma la a ri to
Sapa too long for me o ti to
Big big man ni mo fẹ ma baro
Mo fẹ ja benz pẹlu camaro
[Chorus]
Isalẹ-Eko wọn o ṣere
Adeniji, Eko akete
Lagos Island wọn ma ṣa ẹ lẹgba
Ọmọ Mainland, awọn ọmọ ọlọba
Ninu Mushin wọn o gbọ paa
Lekki boiz wọn maa n tẹwo si aza
Inu Alaba n'ọn ti maa n naja
Owo lemi n wa emi o waja
[Verse 3]
Aye yii na turn by turn
Lowkey my brother no dey rush
If you no wish your brother fall
Aje to ba ti ni igbagbọ
E go soon be like say you bribe God
Them wonder bi mo ṣe jẹlọ
Lowkey ni mo n gasolo
Aje, a jura wa lọ
[Chorus]
Isalẹ-Eko wọn o ṣere
Adeniji, Eko akete
Lagos Island wọn ma ṣa ẹ lẹgba
Ọmọ Mainland, awọn ọmọ ọlọba
Ninu Mushin wọn o gbọ paa
Lekki boiz wọn maa n tẹwo si aza
Inu Alaba n'ọn ti maa n naja
Owo lemi n wa emi o waja
Written by: Mujeeb Oladimeji
instagramSharePathic_arrow_out