Lyrics
For your sport betting (1960 lo le ṣe)
For your sport betting (1960 lo le ṣe)
Visual bet (bẹ lowo ń wọle)
Visual bet o (bẹ lowo ń wọle)
Mo tá, mi o jẹ, o sí o
(1960 ń sanwo)
Mo tá, mi o jẹ, o sí o
(1960 ń sanwo)
Dọtun ọmọ Adegbile
Lati Arawu area mi, ma gbọ mí mo ṣe kọrin mi
Mo tá, mi o jẹ, o sí o (1960 ń sanwo)
Aja ń sare
Ẹṣin ń sáré
Baby ń ṣẹ'jù
Goal-goal, straight win (1960 a sanwo)
Goal-goal, straight win (1960 a sanwo)
Anybody win, 1.5 ni
1960, owo ńlá
Anybody win, 2.5 ni
1960, owo ńlá
One x
Two x
First half win
Second half win
Anybody win, 2.5 ni
1960, owo ńlá
Anybody win, 2.5 ni
1960, owo ńlá
Anybody win, 2.5 ni
1960, owo ńlá
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com