Credits
PERFORMING ARTISTS
K1 De Ultimate
Performer
Olasunkanmi Wasiu Ayinde Marshal
Lead Vocals
COMPOSITION & LYRICS
K1 De Ultimate
Songwriter
Lyrics
Àwa dé o
Àwa ni,awá ni
Àwa dé o
Àwa ni,awá ni
Àwa naa kọ Ọlọhun ọba mà mà ni
Àwa ni
Mo l'awá naa kọ Ọlọhun ọba mà mà ni
Àwa ni
Òjò ń rọ,afẹfẹ'nfẹ lẹlẹ
Àwa ni
Tẹ bá ti rí Àyìndé ẹ má sọ rọ' o
Irán igún níí jẹbọ
B'oluwa ba fún Ayinde ẹ má sọ rọ' o
Irán igún níí jẹbọ
Ijó o,ijó,ijó
Eré ó,eré,eré
Eré ó,eré,eré
Ijó o,ijó,ijó
Awa o lóhun meji kasa ti lulu kẹjo
Irán igún níí jẹbọ
Ijó o,ijó,ijó
Eré ó,eré,eré
Eré ó,eré,eré
Ijó o,ijó,ijó
Ala wa o lóhun meji kasa ti lulu kẹjo
Irán igún níí jẹbọ
Ẹyin lẹ o ma wa,awa lẹ o ma ba
Al'ẹyin lẹ o ma wa,awa lẹ o ma ba
Ayinde lọ ní fuji ti o la fi we
Ojo lọọkọ àgbàdo
Ẹyin lẹ o ma wa,awa lẹ o ma ba
Al'ẹyin lẹ o ma wa o,awa lẹ o ma ba
Ayinde lọ ní fuji ti o la fi we
Ojo lọọ'kọ àgbàdo
Robo-robo ke n gé ó, àrà ke n gé
Robo-robo ke n gé ó, àrà ke n gé
Ọwá di olobiripo,ipò to fi jó
Má jó sọ tún ma jó sosi
Gbọwọ ijó gengen
Ọwá di olobiripo,ipò to fi jó
Má jó sọ tún ma jó sosi
Gbọwọ ijó gengen
Robo-robo ke n gé ó,ara ke n gé
Robo-robo ke n gé ó,ara ke n gé
Ọwá di olobiripo,ipò to fi jó
Má jó sọ tún ma jó sosi
Gbọwọ ijó gengen
Ọwá di olobiripo,ipò to fi jó
Má jó sọ tún ma jó sosi
Gbọwọ ijó gengen
Ọwá di olobiripo,ipò to fi jó
Má jó sọ tún ma jó sosi
Gbọwọ ijó gengen
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com