Top Songs By Tope Alabi
Similar Songs
Credits
COMPOSITION & LYRICS
Tope Alabi
Songwriter
Lyrics
Lati inu oyun titi di omo owo o
Igba mo wa lomo owo awon ota gba wipe iku o pa mi
Mo ra ko ro de ile olodia awon ti o fe n waye rara
Baba o sho mi, ore re yi o lakawe
Lati irakoro titi di omo irinse o sho mi o
Titi mo fi wa di agbalagba o
Igba ti mo ro, ise iyanu re laye mi
Mo wa ri pe o oga o pupo
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi
Mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi
Mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo
Ogun ti eniyan ja n'agba, o poju ogun igba ewe lo
Tori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju ko
Idi ti aye fin le ni, oye aye, Olorun mi mo o
Oju ogun laye je feni to waye o wa se rere
Mo wa ronu jinle aanu re lori aye mi
Emi ri pe o ga o pupo o
Igba ti mi ro anu re lo ri mi
Mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba
Igba ti mo ro anu re lo ri mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi
Mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo
Ose Olorun, Iwo lo je ki ewu aye fo mi da
Iya to je mi, o je ko je mi gbe o, Baba o seun
A pe omo lowo eyin
Oluso agun fun mi, Olorun iwo ni
Iwo lo gbe mi ro, eniyan o le seyi o afi iwo
O gbe mi so ke gogoro, osuba re o Baba
Eyi ni mo se isiro fun titi, ogbon ori mi ko gbe
Igba ti mi ro ife nla re lori mi
Mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba
Igba ti mo ro ife nla re lori mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi
Mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo
Olorun to ga owa loke
Olorun to be ninu aye
Okere titi, ogba mimo eniyan
Owa lotun wa, owa lo si wa
Ayika wa gbogbo, owa ni be
Ohun ni Olorun, afeti lu kara
Larin alawo dudu o n sise e lo
Eyin re eniyan, mo rin ise re
Alawo funfun won teriba fun
Alayi mo n kon, won beere wipe
Tani Olorun, ta l'Olorun
Ayanfe ema da won lo wun pe
Ibi gbogbo lo wa eh (Ibi gbogbo lo wa)
Olorun agbaye ibi gbogbo lo wa (Ibi gbogbo lo wa)
Ani ko si ibiti oju Olorun ko to (Ibi gbogbo lo wa)
Olorun nla apejuba, arayerorun (Ibi gbogbo lo wa)
Ibi gbogbo l'Olorun gbe (Ibi gbogbo lo wa)
O nbe laye, emi awon woli to to ni (Ibi gbogbo lo wa)
Oro gbe inu omo eniyan fo mu (Ibi gbogbo lo wa)
Oti saju aye de, omo inu aye ati eyin aye (Ibi gbogbo lo wa)
Ibi gbogbo lo wa Olodumare (Ibi gbogbo lo wa)
O nbe larin awon angeli mimo (Ibi gbogbo lo wa)
Ko si ibiti e pe olorun si ti o wa oh (Ibi gbogbo lo wa)
Ibi gbogbo lo wa baba oh (Ibi gbogbo lo wa)
Olorun ajanaku, ibi gbogbo lo wa Baba (Ibi gbogbo lo wa)
O nbe lokan re ti o ba gba laye (Ibi gbogbo lo wa)
Ibi gbogbo, ibi gbogbo lo wa (Ibi gbogbo lo wa)
Written by: Tope Alabi