Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Tope Alabi
Tope Alabi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Patricia Temitope Alabi
Patricia Temitope Alabi
Songwriter

Lyrics

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo n kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o eh
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo n kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o eh
Didara orun, o n so togo Re o Olorun
Ewa Re to yi aye ka, n so togo Re o bo ti po to
Gbogbo eda, eranko at′ewebe n yin O oh
Ise owo Re gbogbo loke nile, won n yin O oh Baba
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o eh
Ola lo wo laso, ogo lo fi pa kaja orun
Ipa ese Re, o n han l'ori apata
Esin Re n fogo yan, l′ori awon okun o Olola nla
Kini yo waa se mi, ti n o j'okele yo, ti n o ni le juba Re Oba
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o eh
Gbogbo eemi inu mi, o n yin O yato oh, Olorun mi
Iwo to mu mi la ina koja, to fi mumi goke, kini mba fi fun O
Kini mo to si ninu oore ofe ti mo ri gba lodo Re
O ba aye mi da majemu lati 'nu ole
Oro Re ye, o si se
Oba ti ki i dale oro Re
Iwariri ni n o ma fi juba Re oh
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o eh
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o eh
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o eh
Written by: Patricia Temitope Alabi
instagramSharePathic_arrow_out