Lyrics

Eru ogo re bami
Eru ogo re bami o
Eleni ogo
Onite ogo
Alade ogo
Ololainu ogo
Elewa ogo
Kikidaogo ogo
Akodaogo ogo
Ogoninu ogo
Asaju ogo
Igbeyin ogo
Eru ogo re bami o
Eru ogo re bami
Eru ogo re bami o
Eleni ogo
Onite ogo
Alade ogo
Ololainu ogo
Elewa ogo
Kikidaogo ogo
Akodaogo ogo
Ogoninu ogo
Asaju ogo
Igbeyin ogo
Eru ogo re bami o
Boti n gbe ninu ogo
O n sogo lori ite o
Ogo lo wo laso
Oloju ogo ni
Eda orun fogo fun aramanda ogo to yii won ka
Baba ologo julo to da ohun gbogbo pelu ogo
Eru ogo re bami
Eru ogo re bami o
Eleni ogo
Onite ogo
Alade ogo
Ololainu ogo
Elewa ogo
Kikidaogo ogo
Akodaogo ogo
Ogoninu ogo
Asaju ogo
Igbeyin ogo
Eru ogo re bami o
Boti leruniyi to
Ite idajo taanu togo
Ogo otun iseju si iseju
Ewa ti o lakawe
Nigbogbo igba sigba
Ododo logo re
Awon orile-ede gbogbo n sola lori ogo re
Eru ogo re bami
Eru ogo re bami o
Eleni ogo
Onite ogo
Alade ogo
Ololainu ogo
Elewa ogo
Kikidaogo ogo
Akodaogo ogo
Ogoninu ogo
Asaju ogo
Igbeyin ogo
Eru ogo re bami o
Olorun to ta sanmo pelu ogo
Iwo lasaju ologo to leruniyi iba baba iba
Alogoleru, toloke
Eleruniyi, tonile
Onile ola, alade ogo
Ofi kikida ogo, shakiti ara
Ogo eleru, ologo gbonla
Jehova, Oba Ologo
Aiye n wa riri Oba eleru lo
Ema bami gbe o Olorun to ju olorun lo
(E bami gbe ga e bami pe Olorun awon olorun)
E bami pe o Olorun aiyeraye
(E bami gbe ga e bami pe Olorun awon olorun)
E ma bami gbe o Olorun a to bi ju
(E bami gbe e e e bami gbe oun lo l'ogo ju lo)
E bami gbe ga oun to so aiye ati orun
(E bami gbe ga, e bami gbe Olorun awon olorun)
E ma bami pe ko gbo Olorun aiyi ku ni o
(E bami gbe ga e bami pe oun lo l'ogo ju lo)
E bami gbe o Oluwa awon oluwa
(E bami gbe ga, e bami pe Olorun awon olorun)
E ma bami gbe ga o Olorun ti kin do ju tini
(E bami gbe, e bami pe oun ki do ju ti ni)
Olorun aiye nit i ko ma ja mi lule
(E bami gbe ga, e bami pe olorun awon olorun)
E ma bami pe o Olorun ti kin dale
(E bami pe e bami pe oun l'ogo ju lo)
Asoro se ni o ti kin soro danu
(E bami gbe e bami gbe oun lo l'ogo julo)
Agbomola ni o ti kin gbomo pa o
(E bami gbe e bami pe Olorun awon olorun)
Ore nla mi lo je o ko je ba ogun aiye mi s'ore o
(E bami gbe e bami gbe oun lo l'ogo julo)
E jowo e bami gbe ga oro ti e na a dayo o
(E bami gbe e bami gbe Olorun awon olorun)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Kabiyesi Oba toto olori aiye
Oni kokoro aiye
Olopo ajobo Kabiyoosi Oba toto, toto, toto
Oba l'Oba tin f'oba je
Alagba la ire awure
Adanikan joba adanikan gori oye
Ko de si eni to le ro o laiye
Oba tin gba idobale oba
Oni ru kere ina olopa ogo
Oba to ti je k'orun ati aiye ko wa
Oba ti iku oni le kan lailai
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Kabiyesi Oba toto olori aiye
Oni kokoro aiye
Olopo ajobo Kabiyoosi Oba toto, toto, toto
Oba to tipe loye ti o si gbo
Oba ti enikeni o fi je
O ni da ina ti o se fi owo pa
Ite re ni ibi to wa ko le si ri lai
Oba igba ani oba igba tuntun
Oba aiye won kin ju aare lo
Oba ti kin yin se aare agbaye o
Oba to le p'oba oba to le ye oba
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Kabiyesi Oba toto olori aiye
Oni kokoro aiye
Olopo ajobo Kabiyoosi Oba toto, toto, toto
Oba to n fi kun odun oba l'aiye
Oba tin gbo ejo Oba tin dajo
Oba ti o se idajo aare gbogbo o
A to gberu afi eru gbo
Oba ti gbogbo aiye o ji yin fun gbeyin
T'oba t'aare ti ijoye gbogbo lo joba le lori
Oba oke bi Oba ile gbogbo o
Mo se Kabiyesi re o Oba toto
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Oba kan wa o (Oba Oba)
Kabiyesi Oba toto olori aiye
Oni kokoro aiye
Olopo ajobo Kabiyoosi Oba toto, toto, toto
Mo se Kabiyesi (Kabiyo o si)
Kabiyoosi (Olori aiye patapata)
Iwo la fe rere kaiye (O ni kokoromaiye lowo)
Kabiyoosi (Kabiyesi ni e banse)
Kabiyesi (Kabiyesi o)
Kabiyoosi (Royal majesty)
Mof'ogo fun oruke re (Your excellency)
Kabiyoosi
Kabiyesi (Iwo lo ko gbgogbo aiye jo)
Kabiyoosi o, mo fori bale fun ori ade l'orun
Kabiyoosi
Kabiyesi
Kabiyoosi o
Mof'ogo fun oruke re
Kabiyoosi
Kabiyesi
Kabiyoosi o
Mof'ogo fun oruke re
Kabiyoosi
Written by: Patricia Temitope Alabi
instagramSharePathic_arrow_out