Top Songs By Tope Alabi
Credits
PERFORMING ARTISTS
Tope Alabi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Patricia Temitope Alabi
Songwriter
Lyrics
[Chorus]
Eh eh eh, eh eh eh
Ah ah ah, ah ah ah ah
Oh oh oh, oh oh oh oh
Mo ri iyanu, eh eh, iyanu
Mo ri iyanu, eh eh, iyanu
Eh eh eh, eh eh eh
Ah ah ah, ah ah ah ah
Oh oh oh, oh oh oh oh
Mo ri iyanu, eh eh, iyanu
Mo ri iyanu, ah ah, iyanu
[Verse 1]
Bawọn kan ba Kuse nigba kan laye won
To ba d'olowo, wọn sọ wipe iyanu ni
B'elo miran ba yàgan ri to ba wa d'ọlọmọ eh eh
Wọn sọ pe iyanu ni, lootọ ni, iyanu ni
B'oko bá danu to run jege, tẹni kankan o f'arapa
Ẹni orí re pe nilẹ ta ro pin tỌlọrun wa gbé e ga
Tabi ẹni to gbọjọ iku to palẹmọ ti o pada wa ku mọ
Gbogbo rẹ lo jẹ iyanu, eh eh o, iyanu ni
[Chorus]
Eh eh eh, eh eh eh (Gbogbo rẹ lo jẹ iyanu)
Ah ah ah, ah ah ah ah (Ninu aye ta wa yii iyanu pọ rẹpẹtẹ)
Oh oh oh, oh oh oh oh
Mo ri iyanu, eh eh, iyanu (Mo ri iyanu, emi ma ri yanu)
Mo ri iyanu, ah ahh, iyanu ni
[Verse 2]
Iyanu to se kenke, o ka mi laya titi
Ilu kekere kan wa wọn o tọrọ jẹ bẹẹ ni wọn o la wọn ṣagbe
Arabirin kan wa nibẹ ta jiṣẹ fún pe o maa bi iyanu
Ẹda eniyan o lero, pe iyanu le ti bẹ wa o
O kuku ṣẹlẹ bẹẹ a bimọ naa, bi o tilẹ jọ iyanu
Ṣugbọn bi ti jọ iyanu to, ọba ilu kan n wa kiri
O n wa lati pa tori ẹ o pọpọlọpọ ọmọ
Ẹ gbọ ki ni ijọloju ki lo fẹ fọmọ talaka ṣe?
B'aye ṣe ri niyẹn ẹni maa ga oju rẹ a ri to (Abi ẹ o ri o)
[Chorus]
Eh eh eh, eh eh eh
Ah ah ah, ah ah ah ah (Ki lo lowo fẹ fọmọ talaka ṣe o?)
Oh oh oh, oh oh oh oh (Ẹ gbọ na)
Mo ri iyanu, eh eh, iyanu (Emi ma ri iyanu kan)
Mo ri iyanu, ah ahh, iyanu ni
[Verse 3]
O dagba (Iyanu)
Iṣẹ iyanu akọkọ (Iyanu)
Ni Canaan ti Galilee (Iyanu)
Ọrọ ninu Tẹmpili (Iyanu)
Oku ọmọ Jairu (Iyanu)
Barthelomew afọju nkọ (Iyanu)
O deti pada f'eleti (Oloore akaikatan niṣẹ iyanu)
[Verse 4]
Ìyanu tó ga to jọ emi loju ju o
Wọn da Baraba silẹ a mu alaiṣẹ o ma ṣe o
Ikan n ba kan ẹpọn rẹrẹ ata ti o ṣe fi bọju
Pari pari re lori igi agbelebu lo ba sọ po tan
A bẹ o ri (Iyanu)
Aronilára ye ye (Iyanu)
Iya eyi gangan (Iyanu)
Abẹni lọwẹ ẹkun ti (Iyanu)
Iyanu wo lo to eyi ka bi eniyan tori ẹṣẹ araye
Iyanu wo lo to eyi o ki a sọmọ nu tori ẹlẹṣẹ park
I ba jẹ awa loun ṣe al e ṣe, ẹ jẹ a bi'ra wa?
Ka ma dena pẹnu akọ iṣẹ ọba ranni iyanu ni
[Chorus]
Eh eh eh, eh eh eh (ọjọ mi loju ju)
Ah ah ah, ah ah ah ah (Mi o le ṣakawe rara)
Oh oh oh, oh oh oh oh
Mo ri iyanu, eh eh, iyanu (Ah iyanu to la mi lẹnu silẹ dẹrẹdẹrẹ)
Mo ri iyanu, ah ahh, iyanu ni
[Verse 5]
Ko sẹbọ ko se tutu to kọjá ẹni f'ẹmi rẹ le'lẹ
Ko tún sí ìfẹ atata kan tó dàbí ìfẹ oluwa
Abi ẹni wa saye lati wa kẹṣẹ ayé gbogbo lọ
Ko tún sí iyanu mirian mo, eyi ni yanu
Oku asi sìn, ojijakadi ni saare
O gba Kokoro lọwọ ikú, ọ gbe iku mi ni isegun
Iku oro re da óò, isa oku isegun re da óò?
Ora ìyè aráyé ni ipo oku, ojinde lọjọ kẹta (Oluwa ji o)
Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lo
Ojinde, tiyetiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni tó fẹ iye ko ka lọ
Ojinde, tiyetiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lọ
Ojinde, tiyetiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lọ
[Verse 6]
Itan iyanu t'ifẹ nla le yi o
Latọdọ baba, Eledua, baba wa
Ẹni ṣaanu gbogbo wa to fọmọ rẹ ra arayé pada
Agba iyanu tobi iyanu teniyan n ri
Iyan iyanu t'ifẹ nla leyi o
Latọdọ aṣẹda, Eledua, baba wa
Eni fìfẹ da wa ti o fẹ ka parun
Agba iyanu to bi iyanu teniyan n ri
Itan iyanu t'ifẹ nla leyi o
La tọwọ ifẹ, Eledua, baba wa
Ẹni gbawa silẹ to f'ọmọ kan ṣoṣo ṣawotan ẹsẹ wa
Agba iyanu to ni iyanu teniyan n ri
Written by: Patricia Temitope Alabi