Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Folarin Usman Babatunde
Folarin Usman Babatunde
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Folarin Usman Babatunde
Folarin Usman Babatunde
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Soundboi Beatz (Let Him Nak)
Soundboi Beatz (Let Him Nak)
Producer

Lyrics

Let him knack!
Folarin Olorin
Ah zoom zoom
Te ba nje lamba mi bi awurebe (hmm)
Kil'owa ninu ori ire taani le se (ahba)
Mo mo mio duro l'egbe jegede
Funmi l'omo to se furo bi sandra benede
Holy father (fada keresi)
Ma funmi l'omo inira (biiti jabesi)
Awon omo tan o kin ni transport fare
Ma gbe wa funmi baba I'm not available
Funmi lomo ayo bi Halima
Ohun Lo mo ibi ti kokoro ile mi wa
O mo pe oju kan l'ada ni ko ni tori suya lo l'adi fun mesuya
Alimama ali (hmmm)
Ali bi ofili ganga (ahh)
Eni'ba fe je'se ali (hmmm)
Oni lati ni nkan gbangba
Alimama ali (hmmm)
Ali bi ofili ganga (ahh)
Eni'ba fe je'se ali (hmmm)
Oni lati ni nkan agba
(Ojigbi jigbi jigbi)
(Alima darijimi)
(With you I want to born pikin)
(Mi o s'eremode baby I'm not kidding)
Alima nkemi o fi ara pe mi
Nibi to le de bi fan lose nfemi (l'eko)
Aada kama ba bayi lo o
Iwa ati furo loje kin fe ba ali lo o
Ise to dun Mofe gbegesi (gbege)
Mo fe to wo mo fe debe (kin debe)
Mo fe tear nylon ati label (label)
To igbo ba kunbe mo ma se bee (se be)
Alimama ali (hmmm)
Ali bi ofili ganga (ahh)
Eni'ba fe je'se ali (hmmm)
Oni lati ni nkan gbangba
Alimama ali (hmmm)
Ali bi ofili ganga (ahh)
Eni'ba fe je'se ali (hmmm)
Oni lati ni nkan agba
(Ojigbi jigbi jigbi)
jigbiiii
(Alima darijimi)
(With you I want to born pikin)
(Mi o s'eremode baby I'm not kidding)
Written by: Folarin Akorede Babatunde, Folarin Usman Babatunde
instagramSharePathic_arrow_out