Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Yusuf Abubakar Sodiq t/as CDQ
Performer
Sunday Ginikachukwu Nweke t/as Masterkraft
Performer
Olajuwon Oluwaseun Opeyemi t/as Islambo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Yusuf Abubakar Sodiq t/as CDQ
Composer
Sunday Ginikachukwu Nweke t/as Masterkraft
Composer
Olajuwon Oluwaseun Opeyemi t/as Islambo
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Sunday Ginikachukwu Nweke t/as Masterkraft
Producer
Lyrics
[Intro]
Awọn girls wọn ki i jẹ n sinmi
Anytime dem see me wọn a ni ṣọmọ lo dun bayii
Ṣọmọ lo dun bayii
Bi o ti ẹ jẹ ọkọ ẹni, ṣo ma jẹ ale ẹni
Wọn ani ṣọmọ lo dun bayii
Ṣọmọ lo dun bayii
[Verse 1]
Before when owu dey blow me, now boys don disembark
I say sapa show me ṣege now pocket is endowed
I smell nice, I look good, I stay fly, no chill
Boys blow from Lagos to London even ni Southy no sleep
Everyday gba btc, ayẹwo n lọ id.me
Ninu ilejo dawo soke kawọn maami pariwo, wọn a ni pe
Olololoooo, ayayayaaa (Wọn a ni pe)
Olololoooo, ayayayaaa
[Chorus]
Awọn girls wọn ki i jẹ n sinmi
Anytime dem see me wọn a ni ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Bi o ti ẹ jẹ ọkọ ẹni, ṣo ma jẹ ale ẹni
Wọn ani ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Ọmọ lo dun bayii (Mwah)
[Chorus]
Awọn girls wọn ki i jẹ n sinmi
Anytime dem see me wọn a ni ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Bi o ti ẹ jẹ ọkọ ẹni, ṣo ma jẹ ale ẹni
Wọn ani ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Ọmọ lo dun bayii (Mwah)
[Verse 2]
Boy so fresh, so clean and handsome
Girls dey fill me like JAMB form
Mo ti yo boo fun mi doggy, maa gba
Gbelepawo alaṣakaṣa
Maami, ẹru tankasu yii lẹ ni n ma ti
Lẹ ni ki n gbagati
After round 9 ẹ ni ki ṣe another
Maami awọn ta jọ ṣana da?
All the fine girls yii wọn fẹ jẹ ki n sinmi
Abi na my destiny o ya gba jẹ n sinmi
After round 9 ẹ ni ki ṣe another
Maami awọn ta jọ ṣana da?
Lati inu Dm (She's here for the D)
Wọ inu iyẹwu (Wọrọwọ)
If na lie wọle wa a sabi
O ṣa mọ rate iya Charlie
[Chorus]
Awọn girls wọn ki i jẹ n sinmi
Anytime dem see me wọn a ni ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Bi o ti ẹ jẹ ọkọ ẹni, ṣo ma jẹ ale ẹni
Wọn ani ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Ọmọ lo dun bayii (Mwah)
[Chorus]
Awọn girls wọn ki i jẹ n sinmi
Anytime dem see me wọn a ni ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Bi o ti ẹ jẹ ọkọ ẹni, ṣo ma jẹ ale ẹni
Wọn ani ṣọmọ lo dun bayii (Mwah)
Ọmọ lo dun bayii (Mwah)
Written by: Olajuwon Oluwaseun Opeyemi t/as Islambo, Sunday Ginikachukwu Nweke t/as Masterkraft, Yusuf Abubakar Sodiq t/as CDQ